Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 19 Oṣù Kàrún
- 1971 – Mars 2 jẹ́ fífilọ́lẹ̀ látọwọ́ Ìṣọ̀kan Sòfíẹ́tì.
- 1991 – Àwọn ará Kroatíà dìbò fún ìlómìnira.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1881 – Mustafa Kemal Atatürk, Ààrẹ ilẹ̀ Túrkì 1k (al. 1938)
- 1925 – Malcolm X (fọ́tò), alákitiyan ẹ̀tọ́ aráàlú ará Amẹ́ríkà (al. 1965)
- 1930 – Lorraine Hansberry, akọeré ará Amẹ́ríkà (al. 1965)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1864 – Nathaniel Hawthorne, olùkòwé ará Amẹ́ríkà (ib. 1804)
- 1989 – C. L. R. James, olùkọ̀wé ará Trínídàd àti Tòbágò (ib. 1901)
- 1994 – Jacqueline Kennedy Onassis, Ìyáàfin Àkọ́kọ́ Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà 1961-1963 (b. 1929)
Ṣíṣàtúnṣe ojúewé yìí látọwọ́ àwọn oníṣe tuntun tàbí àwọn oníṣe aláìtíìforúkọsílẹ̀ jẹ́ tí tìpa lọ́wọ́lọ́wọ́. See the protection policy and protection log for more details. If you cannot edit this ojúewé and you wish to make a change, you can submit an edit request, discuss changes on the talk page, request unprotection, log in, or create an account. |