Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 2 Oṣù Kàrún
- 1611 – Bíbélì King James jẹ́ títẹ̀sìwé fún ìgbà àkọ́kọ́ ní London, England.
- 2004 – Ìparun ní Yelwa bá àwọn ada-ẹran bíi 630 ní Nigeria.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1843 – Elijah McCoy, oníhùmö ọmọ Kánádà (al. 1929)
- 1972 – Dwayne Johnson, ẹlẹ́mù àti òṣeré ará Amẹ́ríkà
- 1975 – David Beckham, agbábọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀ ará Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1519 – Leonardo da Vinci, oníhùmö àti akun-àwòrán ará Itálíà (ib. 1452)
- 1998 – Justin Fashanu, agbábọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀ ará Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì (ib. 1961)
- 2011 – Osama bin Laden, apaníra ará Saudi Arabia (ib. 1957)