Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 1 Oṣù Kàrún
Ọjọ́ 1 Oṣù Kàrún: Ọjọ́ àwọn Òṣìṣẹ́ Káàkiriayé
- 1852 – Owóníná pésò Filipínì bọ́ sí ìgboro.
- 1940 – Wọ́n fagilé Ìdíjé Òlímpíkì Ìgbà Oru 1940 nítorí ogun.
- 1948 – Orílẹ̀-èdè Olómìnira àwọn Ènìyàn Kòréà (Korea Àríwá) jẹ́ dídásílẹ̀, pẹ̀lú Kim Il-sung bíi olórí.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1852 – Santiago Ramón y Cajal, aṣesáyẹ́nsì ará Spéìn (al. 1934)
- 1919 – Mohammed Karim Lamrani, Alákóso Àgbà ilẹ̀ Mòrókò
- 1930 – Little Walter, akọri blues ará Amẹ́ríkà (al. 1968)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1976 – T.R.M. Howard, alákitiyan ẹ̀tọ́ aráàlú ará Amẹ́ríkà (ib. 1908)
- 1993 – Ranasinghe Premadasa, Ààrẹ ilẹ̀ Sri Lanka (ib. 1924)
- 1994 – Ayrton Senna (fọ́tò), awakọ̀ ìdíje ará Brasil (ib. 1960)