Wikipedia:Àyọkà ọṣẹ̀ 6 ọdún 2011
Bangladẹ́shì, fun ibise gege bi orile-ede Olominira Araalu ile Bangladesh je orile-ede kan ni Guusu Asia. O ni bode mo India ni gbogbo awon egbe re ayafi fun bode kekere mo Burma (Myanmar) ni guusuilaorun ati mo Ebado Bengal ni guusu. Lapapo mo ipinle West Bengal ni India, o je agbegbe eya-ede Bengal. Oruko Bangladesh tumosi "Orile-ede ile Bengal" ni ede ibise Bengal. Awon bode Bangladesh lowolowo loni je didasile pelu ipinya Bengal ati India ni 1947, nigbati agbegbe na di egbe apailaorun orile-ede tuntun Pakistan. Sugbon, o pinsoto lati egbe apaiworun pelu 1,600 km (994 mi) ile India. Nitori idawaloto oloselu ati ede ati aisi okowo to fa isodi awon araalu si Iwoorun Pakistan, to fa ogun fun ilominira ni 1971 ati idasile orile-ede Bangladesh. Leyin ilominira orile-ede tuntun yi koju iyan, ajalu eda ati aini togbale, ati wahala oselu ati igbajoba ologun. Ipadade oseluaraalu ni 1991 mu itoro ati idagbasoke okowo wa. Bangladesh ni orile-ede keje to lopo eniyan julo ati ikan ninu awon orile-ede to lopo eniyan kikijulo laye pelu osuwon aini giga. Sibesibe, GDP ti enikookan ti di emeji lati 1975, be sini osuwon aini ti re bi 20% lati ibere awon odun 1990. Bangladesh je ikan ninu awon orile-ede ti a npe ni okowo "Next Eleven". Dhaka, oluilu re, ati awon gbongan igboro ilu miran kopa ninu idagbasoke yi. Fun jeografi, orile-ede yi gba ile olora Delta Ganges-Brahmaputra be sini oun ni omoyale lododun ojo monsoon ati iji birikiti. Bangladesh ni ile yepe eti-odo to gunjulo laye ni ti Cox's Bazaar. Oselu re ni oseluaralu ile-asofin. Bangladesh je ikan ninu Ajoni awon Orile-ede, OIC, SAARC, BIMSTEC, ati D-8. Gege bi Banki Agbaye se sakiyesi ninu Oro nisoki Orile-ede re ni July 2005, Bangladesh ti ni ilosiwa gidi ni idagbasoke eniyan ni apa imookomooka, idogba ako/abo ni ile-eko ati iresile ipoju awon eniyan. However, Bangladesh si nkoju awon isoro nla, ajakale iwaibaje awon oloselu ati osise ijoba, economic competition relative to the world, serious overpopulation, widespread poverty, and an increasing danger of hydrologic shocks brought on by ecological vulnerability to climate change. (ìyókù...)