Wikipedia:Ìtọrọ láti di alámòjútó/Oníṣẹ́: tbiw
Àwọn ìfi orúkosílẹ̀ fún alámòjútó tó ń lọ lọ́wọ́lọ́wọ
àtúnṣeÌjíròrò yìí ti parí. Ẹnikẹ́ni kò gbọdọ̀ ṣe àtúnṣe si.
Ọ̀rọ̀ ìforúkọsílẹ̀
àtúnṣeMo fe fi oruko sile lati di alamujoto nitori Yoruba Wikipedia fe atunse ati lati se ida si fun awon oro pataki. Mo fe je ki Wikipedia ti elede abinibi wa te si waju. Mo fe se awon eto onise miran lati gbe Wikipedia Yoruba ga. Ma tete ma dasi oro to ba se kuko.
Ìjíròrò
àtúnṣe- Àwọn ìjápọ̀ fún oníṣẹ́ Àpẹrẹ: Tbiw (talk.contribs.deleted.logs.block log.lu.rfar.rfc.rfcu.ssp.spi)
- A lè rí àwọn àtúnṣe tí oníṣẹ́ Tbiw ti sọ̀rọ̀níṣókí ní ibí.
Jọ̀wọ́ sọ̀rọ̀ tútù tó dára, pẹ̀lụ́ ìrẹ̀lẹ̀. Tí o kò bá mọ oníṣẹ́ tí ó fẹ́ di alábójútó yìí dáradára, Jọ̀wọ́ ṣe àyẹ̀wo àfikún rẹ̀ dáradára kí o tó dási.
RfA/RfB toolbox | |
---|---|
Counters | |
Analysis | |
Summaries | |
Cross-wiki |
Faramọ́ (support)
àtúnṣelòdìsí (oppose)
àtúnṣe- Mo lòdì si - N kò rí àmì ìdánilójú wípé ẹ ní ìmọ̀ tó peregedé láti di alámòójútó tí ń pè fún. Mo sì tún ṣàkíyèsí kò pẹ́ rárá tí ẹ dara pọ̀ mọ́ Wíkì yí.
Ẹ ṣeun.Agbalagba (ọ̀rọ̀) 19:24, 14 Oṣù Kẹ̀sán 2020 (UTC)
- Kò ṣeéṣe largely per this nonsensical report and your poor translations into Yoruba language. I am writing in English as I believe you do not have a good understanding of the Yoruba language. I see that you made several edits in poor Yoruba language that need some proper review. May I respectfully ask that you refrain from making further edits to mainspace articles and or creating further templates until your edits are reviewed? I don't like to enforce this with a block and I want to trust you to respect this request. Pinging User:Demmy. Regards. T CellsTalk 16:55, 15 Oṣù Kẹ̀sán 2020 (UTC)
Ìdásí gbogboògbò (general comment)
àtúnṣeKò tẹ̀síwájú mọ́ per inexperience and some further issues.
Pa cache ojú ewé rẹ́ tí àwọn ìforúkosílẹ̀ kó bá dé ojú ìwọ̀n.