Wikipedia:Ìtọrọ láti di alámòjútó/T Cells 3

Àwọn ìfi orúkosílẹ̀ fún alámòjútó tó ń lọ lọ́wọ́lọ́wọ

àtúnṣe

Àkókò tí a wà lọ́wọ́lọ́wọ́ ni

Ọjọ́ Àìkú 29 Oṣù Kejìlá 2024


Ọ̀rọ̀ ìforúkọsílẹ̀

àtúnṣe

Mo faramo ki T cells te Siwaju gege bi alamojuto.

Ẹpẹ̀lẹ́ o ẹ̀yín ẹlẹ́gbẹ́ mi. Ó wùnmí kín máa bá iṣẹ́ ribiribi mi lọ gẹ́gẹ́ bí alámójútó. Lọ́tẹ̀ yíi mó fẹ́ jẹ́ kí alámójútó mi jẹ́ láílái (permanent). Ọ̀gá mi Oníṣe:Demmy nìkan ni alámójútó láílái tí ó wà níbí, ṣùgbọn ọwọ́ wọ́n máa ń dí. Ó dárá kí a pé méjì síbí torí ìdágìrì. Ẹṣeun. T CellsTalk 11:22, 24 Oṣù Kẹ̀sán 2019 (UTC)

Àwọn ìfi orúkosílẹ̀ fún alámòjútó tó ń lọ lọ́wọ́lọ́wọ

àtúnṣe

Àkókò tí a wà lọ́wọ́lọ́wọ́ ni

Ọjọ́ Àìkú 29 Oṣù Kejìlá 2024


Àkókò ìbò

àtúnṣe

Ètò ìdìbò yí bẹ̀ẹ̀rẹ̀ ní 08:12:25 24/09/19 tí ó sì ma parí ní 08:12:25 01/10/19.

Ìjíròrò

àtúnṣe

Jọ̀wọ́ sọ̀rọ̀ tútù tó dára, pẹ̀lụ́ ìrẹ̀lẹ̀. Tí o kò bá mọ oníṣẹ́ tí ó fẹ́ di alábójútó yìí dáradára, Jọ̀wọ́ ṣe àyẹ̀wo àfikún rẹ̀ dáradára kí o tó dási.

Faramọ́ (support)
àtúnṣe
  • Faramọ́ (support) fún títí láíláí (permanet adminship). T CellsTalk 11:22, 24 Oṣù Kẹ̀sán 2019 (UTC)
  • mo f'ara mo kí User:T Cells di alamojuto fún títí láíláí - Adefanike (ọ̀rọ̀) 11:44, 24 Oṣù Kẹ̀sán 2019 (UTC)
  • Mo faramo (support) E maa ba ise takuntakun yin lo. User:macdanpets 12:11, 24 Oṣù Kẹ̀sán 2019‎
  • Mo fara mọ (Support), mo fẹsẹ̀ si, mo fi gbogbo ara si kí User T Cells ó di alákòóso àti Alámòójútó titi láe láé. Agbalagba (ọ̀rọ̀) 12:58, 24 Oṣù Kẹ̀sán 2019 (UTC)
  • Mo Faramọ́ (support) fún onise T Cells di alákòóso titi láíláí. Kaizenify (ọ̀rọ̀) 04:32, 25 Oṣù Kẹ̀sán 2019 (UTC)
  • Mofaramo ki t cells ma ba ise ribiribi won lo. Zeemahgan (ọ̀rọ̀) 15:10, 25 Oṣù Kẹ̀sán 2019
lòdìsí (oppose)
àtúnṣe
Ìdásí gbogboògbò (general comment)
àtúnṣe

Pa cache ojú ewé rẹ́ tí àwọn ìforúkosílẹ̀ kó bá dé ojú ìwọ̀n.