World Alliance for Breastfeeding Action
Àjọ World Alliance for Breastfeeding Action (WABA) jẹ́ akójọ àwọn ènìyàn tí wọ́n ń ṣiṣẹ́ ní agbáyé láti dẹ́kun ìdènà tí ó débá ifọ́mọlọ́mú kí wọ́n lè mú ìlọsíwájú bá ìpolówó fífún ọmọ lọ́mú. Akójọpọ̀ àwọn ènìyàn wọ̀nyí ń lo àwọn ọ̀nà oríṣiríṣi bíi: Jíjẹ́ ìyá, ẹ̀tọ́ àwọn ònrà láti fẹsẹ̀ ìpolongo yí múlẹ̀ àti fífún omi ọmú, ìkànsíni ati bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. [1][2]
World Alliance for Breastfeeding Action (WABA) | |
---|---|
Type | Network of People |
Ibùdó | Worldwide |
Key people | Derrick and Pat Jelliffe |
Lára àwọn ènìyàn pàtàkì ati lájọ-lájọ tí wọ́n ń kópa nínú ìpolongo yí ni WABA, Derrick and Pat Jelliffe,paediatrics àti ajọ ìlera ọmọdé, ni parapọ̀ láti fi ìpìlẹ̀ ìpolongo yí lélẹ̀ ní Ibẹ̀rẹ̀.[3][4][5][6] Àjọ WABA ni ó gbé ìpolongo World Breastfeeding Week kalẹ̀ ní ọjọ́ kínní oṣù kẹjọ títí di ọjọ́ keje oṣù kẹjọ gbogbo ọdún káàkiri àgbáyé, ìpolongo yí ń wáyé ní àwọn orílẹ̀-èdè ọgọ́rùn-unléláadọ́rin.[7]
Ìpolongo
àtúnṣeOríṣiríṣi ìpolongo ni àjọ WABA ń gbé kalẹ̀, láti 1991 títí di òní, lára rẹ̀ ni Baby Friendly Hospital Initiative (BFHI) tí wọ́n jọ gbé kalẹ̀ pẹ̀lú àjọ UNICEF àti World Health Organization, tí wọ́n fojú sun ilé ìwòsàn tí síṣe àti ìmúlò àwọn ìlànà ohun tí wọ́n ń pè ní Innocenti Declaration.[8]
Ní ọdún 1933, ìpolongo yí gbé ìgbésẹ̀ lórí ìṣòro tí ó ma ń jẹyọ àwọn obìnrin tí wọ́n ń tọ́mọ lọ́wọ́ níbi iṣẹ́ wọn látàrí ibọ́mọdọ́rẹ̀ẹ́ tí àwọn abiyamọ ma ń ṣe. Ohun tí eọ́n fẹ́ níbi iṣẹ́ ni wípé kí abiyamọ ó pa itọ́jú ọmọ àti iṣẹ́ rẹ̀ pọ̀ láì bìkítà ewu tí o lè tibẹ̀ jáde.Àdàkọ:Cn
Ní ọdún 1994, ohun tó jẹ́ afojúsùn àwọn àjọ wọ̀nyí ni wípé kí wọ́n ṣe ìpolongo lórí pàtàkì bí ẹ̀tọ́ àwọn abiyamọ yóò ṣe di òfin nínú ààtò òfin International Code of Marketing of Breast-milk Substitutes jákè-jádò agbáyé láti lè mú itura bá àwọn abiyamọ.Àdàkọ:Cn
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "WHO | World Breastfeeding Week". World Health Organization. Retrieved 11 November 2010.
- ↑ Moen, Christian. "Health facilities are vital in promoting good breastfeeding practices, says UNICEF". UNICEF Media. UNICEF. Archived from the original on 1 August 2017. Retrieved 11 November 2010.
- ↑ "Derrick and Eleanore "Patrice" JELLIFFE - Obituaries (2)". Family History & Genealogy Message Board. Ancestry.com. Retrieved 11 November 2010.
- ↑ G.J.E (4 August 1992). "IN MEMORIAM: Derrick B. Jelliffe". Journal of Tropical Pediatrics 38 (Oxford University Press): 145. http://tropej.oxfordjournals.org/cgi/issue_pdf/frontmatter_pdf/38/4.pdf. Retrieved 11 November 2010.
- ↑ C. Latham, Michael. "A special tribute to Pat Jelliffe". World Alliance for Breastfeeding Action. Retrieved 11 November 2010.
- ↑ Calisphere. "Obituary". University of California. Retrieved 11 November 2010.
- ↑ "LLLI | World Breastfeeding Week Celebration | World Breastfeeding Week Celebrations". La Leche League International. Retrieved 11 November 2010.
- ↑ "The Baby-Friendly Hospital Initiative (BFHI)". WABA Research Task Force (RTF). August 2010. http://www.waba.org.my/whatwedo/research/pdf/rtfnl-aug10.pdf. Retrieved 11 November 2010.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "WHO PDF" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "WHO Book" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "ITCILO" defined in <references>
is not used in prior text.
<ref>
tag with name "Fdate" defined in <references>
is not used in prior text.Àwọn Ìtàkùn ìjásóde
àtúnṣe- World Alliance for Breastfeeding Action Website Archived 2021-04-11 at the Wayback Machine.
- World Breastfeeding Week Website