Yọ̀mí Fash-Láńsò
Yọ̀mí Fash-Láńsò (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ keje oṣù kẹfà ọdún 1968) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré ọmọ bíbí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[1] [2]
Aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ àti ìgbìyànjú iṣẹ́ tíátà rẹ̀
àtúnṣeYọ̀mí Fash-Láńsò kàwé gboyè dìgírì nínú
Yọ̀mí Fash-Láńsò | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Ọjọ́ keje oṣù kẹfà ọdún 1968 |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Lagos. |
Iṣẹ́ | òṣèré |
Notable work | Aje metta |
imọ̀ nípa okowò ní ifáfitì ìjọba àpapọ̀ tí ó wà ní ìpínlẹ̀ Èkó, University of Lagos. Gẹ́gẹ́ bí a ti mọ̀ pé Yọ̀mí di gbajúmọ̀ òṣèré ìlúmọ̀ọ́kà ní sinimá àgbéléwò èdè Yorùbá, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ní àmìn ẹ̀yẹ tí ó ti gbà.[3] [4]
Àtòjọ díè nínú àwọn sinimá àgbéléwò tí ó ti kópa
àtúnṣe- Aje metta
- Jenifa
- Idoti oju
- Opolo
- Tani kin fe?
- Temidun
- Kadara Mi
- Omo Elemosho
- Dazzling Mirage (2014)
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "8 things you should know about talented actor". Pulse Nigeria. 2016-06-07. Retrieved 2019-12-10.
- ↑ PeoplePill (1968-06-07). "Yomi Fash Lanso: Nigerian actor - Biography, Life, Family, Career, Facts, Information". PeoplePill. Retrieved 2019-12-10.
- ↑ "Nollywood/ Nigeria No.1 movies/ films resources online". Nollywood/ Nigeria No.1 movies/ films resources online. 2019-10-21. Retrieved 2019-12-10.
- ↑ "I wore fake wedding ring for years to keep ladies off –Yomi Fash-Lanso". The Punch - Nigeria's Most Widely Read Newspaper. 2014-12-18. Archived from the original on 2014-12-18. Retrieved 2019-12-10. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)