Yinka Davies
Yinka Davies (tí a bí ní ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù keje, ọdún 1970) jẹ́ olórin, oníjó, akọ-orin-kalẹ̀ àti adájọ́ ètò olórin ti Nigerian Idol, ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Yinka ti wà nínú ilé-iṣẹ́ ìdárayá fún bí i ọdún méjìdínlọ́gbọ̀n.[1]
Yinka Davies | |
---|---|
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Yinka Davies |
Ọjọ́ìbí | 16 Oṣù Keje 1970 |
Ìbẹ̀rẹ̀ | Benin /Sierra Leone |
Irú orin | Afrobeat, jazz |
Occupation(s) |
|
Instruments | vocals |
Years active | 2000–present |
Labels | EniObanke |
Associated acts | 5&6 Band, Irewole Samuel Oni |
Website | yinkadavies.com |
Ìpìlẹ̀ rẹ̀
àtúnṣeBàbá rẹ̀ – Ọmọ Benin Republic/ ìran Líṣàbí ti ìlú Sierra Leonetó kó wá sí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà nítorí ọmọ Nàìjíríà ni.
Ìyá rẹ̀ – ó wá láti ìlú Ìkòròdú, ní Ìpínlẹ̀ Èkó.
Ìyá-ìyá rẹ̀ - Ó wá láti ìdílé ọlọ́ba ní ìlú Sagamu.
Àwọn ìdílé tó ti wá yìí nípa lórí àwọn orin tó máa ń kọ. Ó rántí pé bàbá rẹ̀ ní dùrù. Ó sì dàgbà sí fífẹ́ràn orin Sam Cooke, Johnny Cash, Elvis àti Jimmy Dean, nítorí àwọn orin yìí ni bàbá rẹ̀ máa ń gbọ́.
Bí Davies ṣe ń dàgbà, rédíò ní ilé ìyá-ìyá rẹ̀ máa ń wà ní Radio Lagos, èyí tó máa kọ orin ilẹ̀ Afica lóríṣiríṣi, bí i orin Manu Dibango (Cameroun - Makossa), Mmaman Shatta (traditional Northern Nigerian musician), Dan Maria Jos (Northern Nigeria), Orlando Julius (southern Nigeria - highlife), Hadjia Funtua (northern Nigeria), Victor Uwaifo (southern Nigeria - Joromi), Fela (southern Nigeria - Afrobeat) àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.
Àtòjọ àwọn orin rẹ̀
àtúnṣeÀwo orin
àtúnṣe- work (1998
- Emi n’lo (2002)
- Black Chiffon (2010)[2]
Orin àbákọ
àtúnṣe- I want to praise (Florocka)
- Lagbaja
- Fatai Rolling Dollar
- Alhaji Sikiru Ayinde Barrister
Àwọn àgbéjáde rẹ̀ tó gbajúmọ̀
àtúnṣe- Alex O's Background Vocalist (1990-1992)
- World Music Day Organised by Alliance Francaise (1995 till date)
- Emi Nlo Album Listening by Carl Raccah (2000)
- Yinka Davies in Concert with *5 & 6* Band at the Alliance Francaise Lagos Nigeria (2013, 2014, 2016)
- Jazzville 7th Anniversary concert under direction of Elder Steve Rhodes
- 1999-2002 – she was the resident act at the Nicon Nuga Hilton Hotel in the Nigerian capital city of Abuja.
- 2006 performed with Tony Allen at The Cave during the release of his record Lagos No Shaking.
- African Film Festival Tour - Milan, Tunis, organised by The Goethe Institute.
- Black Chiffon Album Launch (2011)
- Nigerian Idol Judge (2011, 2012, 2013, 2014, 2016)
- Ajumogobia Science Foundation Concerts (2005-2015)
- African Music Festival - London (2015)
- Lagos State Jazz Festival (2016, 2017, 2018)
- Calabar State Jazz Festival (2017)
- Jazz at The United States Consulate's Residence (2015....)
Tíátà àti orí-ìtàgé
àtúnṣe- Things Fall Apart directed by Bassey Effiong (1988)
- Lion and The Jewel directed by Bassey Effiong (1988)
- Contemporary Dance Troup led by Elizabeth Hammond (1988–90)
- Wind vs Polygamy directed by Sam Loco Efe (1989)
- Kakaki Concert: directed by Ben Tomoloju (1990)
- Death and The King's Horseman directed by Bayo Oduneye (1990)
- Greener Grass directed by Niji Akanni and Bakare (1990)
- Irara Alagbe directed by Felix Okolo (1992)
- Mekunu Melody by Felix Okolo (1992)
- Area Boy by Felix Okolo (1993)
Àwọn àmì-ẹ̀yẹ tó gbà
àtúnṣe- FAME music—Upcoming artiste of the year, 1992
- Nigeria Music Award (NMA)—Voice of the Decade, 2007.[3]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "I was too playful my sons couldn't grow up with me-Yinka Davies". 4 May 2019.
- ↑ "Yinka Davies and 5&6: Black Chiffon – The album | wongawong". Wongawong.wordpress.com. 2011-02-19. Retrieved 2013-07-25.
- ↑ "Yahoo! Groups". Groups.yahoo.com. Archived from the original on June 30, 2013. Retrieved 2013-07-25. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)