Sikiru Ayinde Barrister

Olorin omo orile-ede Naijiria

Sikiru Ayinde Barrister [1] [2] [3]) je olorin fuji omo ile Naijiria. Ayinde Barrister bere si korin ta ni odun 1966- 2008, Barrister gbe awo orin to po to 127 jade. Ninu won ni Oke Agba (1980), Ijo Olomo (1983), Nigeria (1983), Military (1984), Barry Wonder (1987), Fuji Garbage (1988), Music Extravaganza (1990) ati Fuji Waves (1991).

Sikiru Ayinde Barrister
MFR
Ọjọ́ìbíSikiru Ololade Ayinde Balogun
(1948-02-09)Oṣù Kejì 9, 1948
Lagos, Lagos State, Nigeria
AláìsíDecember 16, 2010(2010-12-16) (ọmọ ọdún 62)
St. Mary's Hospital, London, United Kingdom
Burial placeIsolo, Lagos State, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Gbajúmọ̀ fúnRevolution of Fuji and Were music
Àwọn ọmọBarry Showkey, Barry Jhay
Musical career
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíiAlhaji Agba
Irú orinFuji
Occupation(s)Singer-songwriter, entertainer
Years active1965–2010
Associated acts

Ìgbésí Ayé r̀ẹ

àtúnṣe

A bí Síkírù Àyìndé Barrister nínú ẹb́i Sàláwù Balógun ní ìlú Ìb̀adàn, bàbá rẹ̀ Salawu Balógun jẹ́ Alápatà Ẹran, nígbà tí ìyá rẹ̀ jẹ́ Oníṣòwò pẹ́pẹ̀ẹ̀pẹ́. Ó lọ Ilé-Ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti Muslim Mission àti Ilé-Ìwé Model ti Mushin tó wà nílù Èkó. Lẹ́yìn èyí ni ó lọ sí ilé-ìwé àkọ́ṣẹ́-mọṣẹ́ ti Yaba Polytechnic láti kọ́ nípa ìmọ̀ òǹtẹ̀wé àti àwọn iṣẹ́ ọwọ́ mìíràn. Àyìndé Barrister bẹ̀rẹ̀ iṣé orin kíkọ láti ìgbà kékeré rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí 'Ají-Sààrì' tàbí Ají-wérẹ lásìkò Àwẹ̀ àwọn Musulumi; bí ó ṣe ń ṣiṣẹ́ rẹ̀ náà ló ń kọrin pẹ̀lú rẹ̀ . Ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí Atẹ̀wé fún Ilé-Iṣẹ́ tí ó pọn ọtí Nigerian Breweries, lẹ́yìn náà ni wọ́n gbà gẹ́gẹ́ bí òǹtẹ̀wé ránṣẹ́ ní Ilé-Iṣẹ́ Ológun Ilè Nàìjíríà Nigerian Armylát̀arí akitiyan rẹ̀́, lásìkò ogun abẹ́lé.</ref>[4] Ó ṣíṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí Ọmọ ogun ní Ẹ̀ka kẹwàá '10th Brigade' ti ìpín Kejì '2nd Division' ti Ilé-Iṣẹ́ Ológun Nàìjíríà lábẹ́ Ọ̀gágun 'Adéníran' ó sì jà fitafita ní Awka, Abagana àti Onitsha.

Ikú àti ìsìnkú rẹ̀

àtúnṣe

Barrister ku ni ojo 16 osu kejila 2010 ni London nibi to ti lo gba iwosan fun arun ito-suga(diabetes). Isinku re waye ni ogbo ojo osu kejila odun 2010 ni ile re ti o wa ni Eko.[5]






Àwọn ìtọ́ka sí

àtúnṣe
  1. Daniel Miller (1995). Worlds Apart: Modernity Through the Prism of the Local. Psychology Press. pp. 244–. ISBN 978-0-415-10789-1. https://books.google.com/books?id=ISq0p5SgGgIC&pg=PA244. 
  2. "Fuji Musician, Sikiru Ayinde "Barrister", Is Dead". SaharaReporters. 16-12-2010. Archived from the original on 2010-12-20.  Check date values in: |date= (help)
  3. "Ayinde Barrister is dead". 234Next. 16-12-2010.  Check date values in: |date= (help)
  4. Paul Wale Ademowo (1996). The King of Fuji Music: Dr. Wasiu Ayinde Anifowoshe Marshal. Effective Publishers. ISBN 978-978-32208-9-8. https://books.google.com/books?id=YusTAQAAIAAJ. 
  5. Ishola Balogun. "Tears roll down as Ayinde Barrister sleeps". 

Ijapo Internet

àtúnṣe