Yunifásitì ìpínlè Kwara

yunifasiti ipinle ni Nigeria

Yunifásitì ìpínlè Kwárà (Kwara State University, tí a mò sí KWASU) tí o kalè sí malete jé yunifásitì ìjoba ìpínlè kwara, adá yunifásitì ìpínlè kwara kalè ní osù kokanla(November) odun 2009 [1], óun ni Yunifásitì karundinlogorun ti wọn da kalè ní Nàìjíríà. [2][3][4][5]

Yunifásitì ìpínlè Kwara
Yunifásitì ìpínlè Kwara
Látìnì: Kwara State University
Motto'University for community development and entrepreneurship
TypePublic
ChancellorJohnson Adewumi
Vice-ChancellorProfessor Muhammed Mustapha Akanbi
Studentsover 25, 000
Undergraduatesover 20,000
Postgraduatesover 2,000
Doctoral studentsover 500
LocationMalete, Kwara State, Nigeria
CampusRural
NicknameKWASU
Websitewww.kwasu.edu.ng
Gátì Yunifásitì ìpínlẹ̀ Kwara

Òjògbón Abdulrasheed Na'allah ní olori àkókó Yunifásitì náà, oun ní olori yunifásitì náà fun odun mewa(2009-2019), orúko olori yunifásitì náà lówólówó ní Òjògbón Muhammed Mustapha Akanbi, yunifásitì ìpínlè Kwara ní ogun egbèrún akeko [6]. Adá yunifásitì ìpínlè kwárà kalè labé isejoba Dokita Bukola Saraki gege bí Gomina ìpínlè Kwara.[7]

Àwon Ìtókasí

àtúnṣe
  1. "About Us". KWASU |. 2020-06-15. Retrieved 2022-03-03. 
  2. "About Kwasu". Retrieved 18 March 2011. 
  3. "KWASU has no affiliation with Ekiti Study Centre - Management" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-09-08. Retrieved 2021-08-15. 
  4. "Hostel fee: KWASU students lament school policy". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-04-12. Retrieved 2021-08-15. 
  5. "Kwara State University students agitated over proposed tuition fee hike". International Centre for Investigative Reporting (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-09-10. Retrieved 2021-08-15. 
  6. "KWARA STATE UNIVERSITY.". Glimpse Nigeria. 2020-07-01. Archived from the original on 3 March 2022. Retrieved 2022-03-03. 
  7. "Kwara State University - AFRIK'EDUC". AFRIK'EDUC | Le Portail de l'Enseignement Supérieur en Afrique (in Èdè Faransé). 2013-06-01. Archived from the original on 3 March 2022. Retrieved 2022-03-03.