Zulumoke Oyibo jẹ́ aṣàgbájáde fíìmù àgbéléwò àti ọ̀kan lára àwọn olùdásílẹ̀ Inkblot Productions, tó sì jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1] Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn obìnrin tí Variety Women's impact ṣàfihàn nínú ìjábọ̀ wọn fún ọdún 2022.[2]

Zulumoke Oyibo
Ọjọ́ìbíZulumoke
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iṣẹ́Producer
Notable workDay of Destiny, The blood covenant, the Perfect Arrangement

Iṣẹ́ tó yàn láàyò

àtúnṣe

Gẹ́gẹ́ bí i aṣàgbájáde fíìmù àgbéléwò, ó ṣàgbájáde fíìmù àgbéléwò Up North ní ọdún 2018 àti Palava.[3][4]

Zulumoke dábàá The Inkblot Women In Film (IWIF) èyí tí wọ́n dá sílẹ̀ láti lè ma rí sí ọ̀rọ̀ àwọn òṣèrébìnrin tó máa ń kópa nínú fíìmù àgbéléwò.[5][6] Pèlú Chinoza Onuzo àti Damola Adewale, ó ṣàgbájáde ètò orí aféfẹ́ kan tí ó pè ní Inkblot's Meet and Greet ní ọdún 2021.[7]

Àtòjọ àwọn fíìmù rè

àtúnṣe

Lára àwọn fíìmu tó ti ṣàgbájáde ni;

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Inkblot Productions marks 10 years of upscaling Nollywood". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-12-29. Archived from the original on 2022-12-14. Retrieved 2022-12-14. 
  2. "Zulumoke Oyibo, Kate Winslet, Mo Abudu, Others Recognised In Variety's Women's Impact Report 2022". thisdaylive.com. Archived from the original on 2022-12-14. Retrieved 2022-12-14. 
  3. "‘Palava’ screened in Lagos". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-12-10. Retrieved 2022-12-14. 
  4. "Making Nigeria's biggest scale film: Producer Zulumoke Oyibo reflects on Up North". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-12-27. Archived from the original on 2022-12-14. Retrieved 2022-12-14. 
  5. Rapheal (2021-05-12). "Women group calls for better structure in Nollywood". The Sun Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-12-14. 
  6. "Zulumoke Oyibo hosts April edition of Inkblot Women in Film (IWIF) in Lagos". Pulse Nigeria. 2021-04-16. Retrieved 2022-12-14. 
  7. "Naz, Zulu and Damola launch Inkblot meet and greet". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-03-25. Retrieved 2022-12-14. 
  8. "Inkblot Premieres 'The Blood Covenant'". thisdaylive.com. Archived from the original on 2022-12-14. Retrieved 2022-12-14.