Day of Destiny
Day of Destiny tí a tún mọ̀ sí D.O.D jẹ́ fíìmù àgbéléwò ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, èyí ti Akay Mason kọ tí ó sì darí pẹ̀lú Abosi Ogba.[2] Lára àwọn akópa fíìmù yìí ni Olumide Oworu, Denola Grey, Norbert Young àti Toyin Abraham.[3][4] Fíìmù náà dá lórí ìrìn-àjò kàyéfì tí àwọn ọmọ-ìyá méjì rìn. Ó jẹ́ ìrìn-àpadàsẹ́yìn sínú àwọn ọdún tó ti kọjá láti mú ìyípadà bá ọrọ̀ ìdílé náà.[5] Ó sì jẹ́ fíìmù Nàjìríà àkọ́kọ́ tó máa níṣe pẹ̀lú ìrìn-àjò kàyéfì, tó sì tún jẹ́ èyí tí wọ́n padà sí àwọn ọdún tó ti kọjá. Ó tún jẹ́ fíìmù alákọ̀ọ́kọ́ tí ó jáde ní ọdún 2021.[6][7]
Day of Destiny | |
---|---|
Fáìlì:Day of Destiny.jpg | |
Adarí | Akay Mason Abosi Ogba |
Olùgbékalẹ̀ | Akujobi Victoria and Isioma Osaje |
Òǹkọ̀wé | Akay Mason Abosi Ogba |
Àwọn òṣèré | Olumide Oworu Denola Grey Norbert Young Toyin Abraham |
Orin | Gray Jones |
Ìyàwòrán sinimá | Barnabas Emordi |
Olóòtú | Victoria Akujobi |
Ilé-iṣẹ́ fíìmù | Anthill Productions Inkblot Productions and Anakle Films |
Déètì àgbéjáde |
|
Orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Èdè | English |
Owó àrígbàwọlé | ₦18.6 million[1] |
Àwọn akópa
àtúnṣe- Olumide Oworu as Chidi
- Denola Grey as Rotimi
- Norbert Young
- Toyin Abraham
- Jide Kosoko
- Blossom Chukwujekwu
- In Dima-Okojie
- Ireti Doyle
- Broda Shaggi
- Tega Akpobome
Ìṣàgbéjáde
àtúnṣe30 October 2020 ló yẹ kí fíìmù yìí jáde tẹ́lẹ̀, àmọ́ wọ́n sun sí 1 January 2021 nítorí ìfẹhónúhàn ti End SARS.[8] 1 January 2021 gan-an gan ní fíìmù yìí jáde, tó sì jẹ́ ọjọ-àjọyọ̀ ọdún tuntun. Ó bọ́ sí ìtẹ́wọ́gbà àwọn ènìyàn, ó sì já sí èrel púpọ̀.[9] 13 July 2021 ni wọ́n ṣàgbéjáde rè sórí Netflix.[10]
Àtòjọ àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀
àtúnṣeYear | Award | Category | Recipient | Result | Ref |
---|---|---|---|---|---|
2022 | Africa Magic Viewers' Choice Awards | Best Art Director | Chris Udomi | Iṣẹ́ ń lọ lórí ẹ̀ | [11] |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Top 20 Films Report 8th 10th January 2021".
- ↑ "Anthill studios is set to release Nollywood's first-ever time travel film titled 'DOD'". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-02-19. Retrieved 2021-01-13.
- ↑ "'Day of Destiny' Berths". THISDAYLIVE (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-01-02. Retrieved 2021-01-13.
- ↑ "'DOD': Everything you need to know about Nigeria's first family adventure film". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-02-21. Retrieved 2021-01-13.
- ↑ "Nollywood Sci-fi Film, Day of Destiny Finally Hits Cinemas Nationwide". Channels Television. Retrieved 2021-01-13.
- ↑ "Watch the teaser for 'DOD' directed by Akay Mason and Abosi Ogba". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-06-29. Retrieved 2021-01-13.
- ↑ "You are being redirected...". businessday.ng. 2 December 2020. Retrieved 2021-01-13.
- ↑ "'D.O.D' producers confirm new release date". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-11-10. Retrieved 2021-01-13.
- ↑ "Here's the official trailer for 'DOD' starring Denola Grey, Toyin Abraham, Blossom Chukwujekwu". Pulse Nigeria. 2020-12-01. Retrieved 2021-01-13.
- ↑ "'DOD', 'Sanitation Day' coming to Netflix in July". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-06-29. Retrieved 2021-09-22.
- ↑ "2022 Africa Magic Awards Nominees don land- See who dey list". BBC News Pidgin. https://www.bbc.com/pidgin/tori-60818021.