Àjọ àwọn Orílẹ̀-èdè
Egbé àwọn Ìjoba Orílẹ̀-èdè
(Àtúnjúwe láti Àgbájọ Ìparapọ̀ àwọn Orílẹ̀-èdè)
Àjọ Ìṣọ̀kan àwọn Orílẹ̀-èdè tabi Àjọ àwọn Orílẹ̀-èdè ni soki (ní èdè Geesi: UNO tàbí UN) jẹ́ àgbájọ káríayé ti eto re je lati fa ifowosowopo ninu ofin kakiriaye, abo kakiriaye, idagbasoke eto inawole, ilosiwaju awujo, eto omoniyan ati imudaju alafia lagaye. OA je didasile ni odun 1945 leyin Ogun Agbaye Keji lati sedipo Apejo awon Orile-ede, lati jawo awon ogun larin awon orile-ede, ki o si pese aye fun ijiroro larin won. O ni opolopo eka akojoegbe kekeke lati le se awon ise wonyi.
Headquarters | New York City (international territory) |
---|---|
Official languages | |
Irú | Intergovernmental organization |
Ọmọ ẹgbẹ́ | 193 member states 2 observer states |
Àwọn olórí | |
António Guterres | |
Amina J. Mohammed | |
Tijjani Muhammad-Bande | |
Mona Juul | |
Dang Dinh Quy | |
Ìdásílẹ̀ | |
• UN Charter signed | 26 Oṣù Kẹfà 1945 |
• Charter entered into force | 24 Oṣù Kẹ̀wá 1945 |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ Official Languages Archived 12 July 2015 at the Wayback Machine., www.un.org. Retrieved 22 May 2015.