Àkójọ àwọn Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ábíá
Èyí ni àkójọpọ̀ àwọn alákòóso àti àwọn gómìnà Ìpínlẹ̀ Abia ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, tí a dá sílẹ̀ ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹjọ (Ògún) ọdún (1991)láti ìgbà tí ó ti dá dúró kúrò lábẹ́ àkóso Ìpínlẹ̀ IMO.
Name | Title | Took Office | Left Office | Party | Notes |
---|---|---|---|---|---|
Frank Ajobena | Military Administrator | August 28, 1991 | January, 1992 | None | |
Ogbonnaya Onu | Executive Governor | January, 1992 | November, 1993 | NRC | |
Chinyere Ike Nwosu | Military Administrator | December 9, 1993 | September 14, 1994 | None | |
Temi Ejoor | Military Administrator | September 14, 1994 | August 22, 1996 | None | |
Moses Fasanya | Military Administrator | August 22, 1996 | August, 1998 | None | |
Anthony Obi | Military Administrator | August, 1998 | May 29, 1999 | None | |
Orji Uzor Kalu | Executive Governor | May 29, 1999 | May 29, 2007 | PDP, PPA | Elected on PDP platform, switched to Progressive Peoples Alliance (PPA). |
Theodore A. Orji | Executive Governor | May 29, 2007 | Present | PPA |
* Military administrators appointed by the ruling dictators of their respective times.
References
àtúnṣe- "Nigerian Federal States". WorldStatesmen. Retrieved 2009-11-30.