Theodore Orji
Olóṣèlú Nàìjíríà
Theodore Ahamefule Orji ni wọ́n bí ní 11/11/1950. Ó jẹ́ olóṣèlú ará ilẹ̀ Nàìjíríà àti Gómìnà Ìpínlẹ̀ Abia láti ọdún 2007 títí dé 2015. Ní ìgbàkan rí ó jẹ́ òṣìṣẹ́ ìjọba àti pé ó jẹ́ olórí àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba ní abẹ́ Gómìnà Orji Uzor Kalu. Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú PDP, lọ́wọ́lọ́wọ́.
His Excellency Theodore Ahamefule Orji CON | |
---|---|
8th Gómìnà ìpínlẹ̀ Abia | |
In office May 29, 2007 – May 29, 2015 | |
Asíwájú | Orji Uzor Kalu |
Arọ́pò | Okezie Ikpeazu |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 1950 Umuahia Ibeku Abia State, Nigeria |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | People's Democratic Party (PDP) |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |