Àkójọ àwọn Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́
Èyí ni àtòjọ àwọn alámójútó àti àwọn Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, ní Nàìjíríà. Wọ́n dá Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ sílẹ̀ ní ọdún 1976-02-03 nígbàtí Western Region jẹ́ pípín sí àwọn ìpínlẹ̀ mẹ́ta ìpínlẹ̀ Ogun, Ondo, àti Oyo.
Name | Title | Took Office | Left Office | Party | Notes |
---|---|---|---|---|---|
Col. David Medaiyese Jemibewon | Governor | 1975 | 1978 | (Military) | |
Col. Paul C. Tarfa | Governor | 1978 | 1979 | (Military) | |
Chief Bola Ige | Executive Governor | 1979 | 1983 | ||
Dr. Victor Omololu Olunloyo | Executive Governor | 1983 | 1983 | ||
Lt. Col. Oladayo Popoola | Governor | 1984 | 1985 | (Military) | |
Col. Adetunji Idowu Olurin | Governor | 1985 | 1988 | (Military) | |
Col. Sasaenia Oresanya | Governor | 1988 | 1990 | (Military) | |
Col. Abdul Kareem Adisa | Governor | 1990 | 1992 | (Military) | |
Chief Kolapo Olawuyi Ishola | Executive Governor | 1992 | 1993 | ||
Navy Capt. Adetoye Oyetola Sode | Administrator | 1993 | 1994 | (Military) | |
Col. Chinyere Ike Nwosu | Administrator | 1994 | 1996 | (Military) | |
Col. Ahmed Usman | Administrator | 1996 | 1998 | (Military) | |
Comm. Pol. Amen Edore Oyakhire | Administrator | 16 August 1998 | 28 May 1999 | (Military) | |
Dr. Lam Onaolapo Adesina | Governor | 29 May 1999 | 28 May 2003 | Oloselu | |
Rasheed Ladoja | Governor | May 29, 2003 | May 28, 2007 | Impeached in January 2006, reinstated in December 2006 | |
Christopher Alao-Akala | Governor (de-facto) | January 12, 2006 | December 7, 2006 | Appointed when Rasheed Ladoja was been impeached, until the impeachment was overturned. | |
Christopher Alao-Akala | Governor | May 29, 2007 | May 29, 2011 | Oloselu | |
Abiola Ajimobi | Gomina Adiboyan | May 29,2011 | May 29,2019 | Oloselu | |
Seyi Makinde | Gomina Adiboyan | May 29 2019 | Present | Oloselu |
See also
àtúnṣeReferences
àtúnṣe- "Oyo State Governors to Date". Oyo State Government. 4 March 2009. Archived from the original on 14 December 2009. Retrieved 30 November 2009.