Bọ́lá Ìgè

Olóṣèlú
(Àtúnjúwe láti Bola Ige)

James Ajibọ́lá Adégòkè Ìgè (September 13, 1930 - December 23, 2001) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà láti ẹ̀yà Yorùbá ní apá ìwọ̀-Oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà. A bi ní ọjọ́ kẹtàlá oṣu kẹsàán ọdún 1930, ó di olóògbé ní ọjọ́ kẹtàlélógún oṣu kejìlá ọdún 2001. [1]̣̣̣̣̣̣̣̣̣́́́́́́́

James Ajibola Ige
Bolaige.jpg
Gomina Ipinle Oyo 2k
In office
October 20 1979 – October 20 1983
LieutenantSunday Afolabi
AsíwájúPaul Tarfa
Arọ́pòVictor Olunloyo
Alakoso Ijoba Apapo fun eto Idajo
In office
January 3 2000 – December 23 2001
Arọ́pòBayo Ojo
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1930-09-13)Oṣù Kẹ̀sán 13, 1930
Esa-Oke
AláìsíDecember 23, 2001(2001-12-23) (ọmọ ọdún 71)
Ibadan
Ọmọorílẹ̀-èdèNaijiria
Ẹgbẹ́ olóṣèlúAction Group, Unity Party of Nigeria, Alliance for Democracy
(Àwọn) olólùfẹ́Atinuke Ige
Alma materUniversity of Ibadan
OccupationAgbejoro

A bí ní ìlú Zaria ni ìpínlẹ̀ (Kaduna) bí o tiḷẹ̀ jẹ́ pé (Èsà-òkè) lébàá Iléṣà ni ìlú rẹ̀. Ìgè jẹ́ gómìnà ìpínlẹ̀ Oyo lati osù kẹwàá ọdún 1979 títí dé osù kẹwàá ọdún 1983. Lẹ́yìn ìgbàtí ìjọ̀ba olósèlú padà dé ní ọdún 1999 Ìgè di Alákòóso ìjọba àpapọ̀ fún ìdájọ́ àti Agbẹjọ́rò-Àgbà ìjọba àpapọ̀̀. O di ọ̀tá pẹ̀lú Oluṣọlá Ọláòṣebìkan fun gbigbemi olóyè Ọbafẹ́mi Awólọ́wọ̀.[2]

Awon Itọ́ka síÀtúnṣe

  1. Kaye Whiteman (1 January 2002). "Bola Ige – Dedicated lawyer building bridges in Nigerian politics". The Guardian (UK). Retrieved 8 November 2009. 
  2. Alhaji Lateef Jakande (27 July 2009). "My Rivalry With Bola Ige". The News. Retrieved 7 November 2009.