Àtẹ fún àwọn ọbẹ̀
Ẹ tún wo: List of soups àti Category:Soups
Èyí ni àtẹ fún àwọn ọbẹ̀ tí ó gbajúgbajà. Ọbẹ̀ jẹ́ àdàpọ̀ àwọn ohun ìsebẹ̀ kan èyí tí a sè láti olómi títí tí ó fi dì pọ̀. Lára àwọn ohun èlò ìsebẹ̀ ni a ti le rí àwọn ẹ̀fọ́ bíi kárọ́ọ̀tì, ànàmọ́, ẹ̀wà, àlùbọ́sà, ata, tòmátò, abbl, èyí tí a máa ń sè pẹ̀lú ẹran bíi màálù, adìẹ, ewúrẹ́, àgùntàn, ṣíkìn, abbl.
Àwọn ọbẹ̀
àtúnṣeOrúkọ | Image | Orírun | Traditional protein | Àpèjúwe àti àwọn ohun èlò |
---|---|---|---|---|
Ají de gallina | Peru | Àkùkọ adìẹ | Peruvian chicken stew | |
Alicot | France | Offal | Ọbẹ̀ tí a ṣe láti ara ẹran adìẹ giblets pàápàá orí, ẹsẹ̀, àti apá | |
Andrajos | Spain (Jaén) | Ẹran ìgbẹ́ | Ọbẹ̀ tòmátò, àlùbọ́sà, garlic, ata rodo, àti ejoro | |
Asam pedas | Indonesia Malaysia |
Ẹja | Ọbẹ̀ tí a fi ẹja àti àwọn ohun èlò mìíràn sè | |
Balbacua | Philippines | Ẹran màálù | Ọbẹ̀ ẹran màálù | |
Bamia | Egypt | Ọmọ ẹran àgùntàn | Ọbẹ̀ tí a sè pẹ̀lú ilá àti ẹran àgùntàn[1][2] | |
Beef bourguignon | France (Burgundy) |
Ẹran màálù | Burgundy]], pẹ̀lú àwọn ohun èlò mìíràn | |
Beef Stroganoff | Russia France |
ẹran màálù | Beef Stroganoff tàbí beef Stroganov | |
Bicol express | Philippines | Ẹran ẹlẹ́dẹ̀ tàbí màálù | Ọbẹ̀ tí a sè láti pẹ̀lú ata àti ẹran màálù tàbí ẹran ẹlẹ́dẹ̀, mílíìkì, ẹja gbígbẹ, àlùbọ́sà, àti ata ilẹ̀. | |
Bigos | Poland Ukraine Lithuania |
Ẹran ẹlẹ́dẹ̀ | Ọbẹ̀ onírúurú ẹran àti àwọn ohun èlò ìsebẹ̀ mìíràn | |
Birnen, Bohnen und Speck | Germany | Ẹran ẹlẹ́dẹ̀ | A máa ń sè é pẹ̀lú ẹran ẹlẹ́dẹ̀ | |
Birria | Mexico | Ewúrẹ́ | Ọbẹ̀ ẹran aláta tí a sè pẹ̀lú ẹran ẹlẹ́dẹ̀, ẹran ewúrẹ́, tàbí ẹran àgùntàn èyí tí wọ́n sáábà máa ń jẹ nígbà ìsinmi lẹ́nu iṣẹ́ bíi ọdún Kérésìmesì | |
Blanquette de veau | France | Veal | Bright veal ragout pẹ̀lú mirepoix | |
Blindhuhn | Germany (Westphalia) |
Ẹran ẹlẹ́dẹ̀ | Ọbẹ̀ àwọn Westphalian èyí tí a máa ń sè pẹ̀lú ẹ̀wà, ẹ̀fọ́ àti bacon | |
Booyah | United States (Upper Midwest) |
Various | Ọbẹ̀ tí ó kún fún onírúurú àwọn ẹran pẹ̀lú ẹ̀fọ́ ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà | |
Bosanski lonac | Bosnia and Herzegovina | Àgùntàn | Ọbẹ̀ àwọn Bosnian tí a máa ń sè pẹ̀lú ẹran màálù, àgùntàn, kárọ́ọ̀tì, ànàmọ́, ata ilẹ̀ abbl | |
Bouillabaisse | France (Marseille) |
Seafood | Ọbẹ̀ ẹja odò pẹ̀lú ẹ̀fọ́ | |
Brongkos | Indonesia (Yogyakarta and Central Java) |
Ẹran màálù | Ọbẹ̀ tí a sè pẹ̀lú ẹran màálù | |
Brodetto | Italy | Ẹja | Ọbẹ̀ ẹja, èyí tí ó yàtọ̀ láti ìletò kan sí èkejì | |
Brudet | Croatia Montenegro |
Ẹja | Ọbẹ̀ ẹja èyí tí a máa ń jẹ pẹ̀lú polenta, tí ó fi ara jọ brodetto àwọn Italian | |
Brunswick stew | United States (South) |
Ẹran ìgbé | Ọbẹ̀ tí a fi tòmátò se, tí ó kún fún ẹ̀wà, àgbàdo, ilá, àti àwọn ẹ̀fọ́, bẹ́ẹ̀ ni a tún le lo àwọn ẹran bíi: Ọ̀kẹ́rẹ́ tàbí Ehoro, ṣùgbọ́n ẹran adìẹ, ẹlẹ́dẹ̀, àti ẹran màálù jẹ́ èyí tí a le lò pẹ̀lú. | |
Trippa alla milanese (Buseca in South America) | Trippa alla milanese.JPG | Italy Argentina Uruguay |
Offal | Ọbẹ̀ àwọn Italian èyí tí a tún lè rí ní Uruguay àti Argentina, ó fi ara pẹ́ callos ti àwọn Spanish |
Buddha Jumps Over the Wall | China | Ẹja | Cantonese variation on shark fin soup | |
Buğu kebabı | Turkey | Ọmọ ẹran àgùntàn | Ọbẹ̀ tí a sè pẹ̀lú ọmọ ẹran àgùntàn àti ẹ̀fọ́ nínú oúnjẹ àwọn Turkish | |
Burgoo | United States (Midwest and South) |
Ẹran ìgbẹ́ | Ọbẹ̀ tí fi onírúurú ẹran ìgbẹ́ sè | |
Cabbage stew | Central Europe | Vegetarian | A máa ń sè é pẹ̀lú cabbage | |
Cacciatore | Italy | Adìẹ | Ọbẹ̀ tí a sè pẹ̀lú ẹran ṣíkìn, ata, àti àlùbọ́sà | |
Cacciucco | Italy | Ẹja | Ọbẹ̀ ẹja tí a fi onírúurú ẹja sè pẹ̀lú ata | |
Cachupa | Cape Verde | Ẹran ewúrẹ́ | Ọbẹ̀ tí a sè pẹ̀lú àgbàdo, ẹ̀wà, ẹja, tàbí ẹran màálù, ewúrẹ́, tàbí ti ṣíkìn. | |
Caldeirada | Portugal | Seafood | Ọbẹ̀ tí a sè tí ó kún fún onírúurú àwọn ẹja, àti ànàmọ́, pẹ̀lú tòmátò àti àlùbọ́sà. | |
Caldereta de cordero | Spain | Àgùntàn | Ọbẹ̀ ẹran àgùntàn | |
Caldo avá | Paraguay | Offal | Ọbẹ̀ tí a sè pẹ̀lú àwọn ìfun ẹran pẹ̀lú àwọn tinú ẹran | |
Caldo gallego | Spain | Ẹran ewúrẹ́ | Ọbẹ̀ ẹran ewúrẹ́ | |
Callaloo | Caribbean West Africa |
Vegetarian | Oúnjẹ àwọn Caribbean | |
Callos | Spain | Offal | Ọbẹ̀ tí ó gbajúmọ̀ ní Spain, wọ́n kà á gẹ́gẹ́ bíi oúnjẹ ìbílẹ̀ àwọn ará Madrid,níbi tí wọ́n ti máa ń pè é ní callos a la madrileña. | |
Caparrones | Spain (La Rioja) |
Sausage | Stew made of caparrón (a variety of red kidney beans) and a spicy chorizo sausage | |
Caponata | Italy (Sicily) |
Vegetarian | Ọbẹ̀ ẹ̀fọ́ | |
Capra e fagioli | Italy (Liguria) |
Ẹran ewúrẹ́ | Ọbẹ̀ tí a sè pẹ̀lú ẹran ewúrẹ́, àti àwọn ohun èlò mìíràn | |
Carbonada | Argentina, Uruguay | Ẹran màálù | Ọbẹ̀ yìí gbajúmọ̀ ní Argentina àti Uruguay | |
Carbonade flamande | Belgium, France | Ẹran màálù | ọbẹ̀ tí a máa ń sè pẹ̀lú ẹran màálù àti àwọn ohun èlò ìsebẹ́ mìíràn | |
Carne mechada | ẹran màálù | Ọbẹ̀ ẹrán àwọn Latin American | ||
Cassoulet | France (Languedoc) |
Adìẹ àti sausage | Oúnjẹ àwọn ará France èyí tí ó kún fún ẹran bíi ti ẹlẹ́dẹ̀ | |
Cawl | United Kingdom (Wales) |
Ẹran àgùntàn | Ọbẹ̀ ẹran àgùntàn àti àwọn ẹ̀fọ́, àti àwọn ìsebẹ́ mìíràn. | |
Chairo | Bolivia | Ẹran màálù | Ẹran àti ọbẹ̀ ẹ̀fọ́ pẹ̀lú chuños, àlùbọ́sà, kárọ́ọ̀tì, ànàmọ́, àgbàdo, ẹran màálù, abbl | |
Chakapuli | Georgia | ẹran àgùntàn | Ọbẹ̀ ẹran àgùntàn tí ó gbajúmọ̀ tí a máa ń fi ata àti àlùbọ́sà sè | |
Chapea | Dominican Republic | Sausage | oúnjẹ ìbílẹ̀ àwọn Dominican Republic | |
Chicken mull | United States (South) |
Fowl | ọbẹ̀ tí ó jẹ́ ti ìbílẹ̀ àwọn North Carolina àti Georgia | |
Chicken pastel | Philippines | Ṣíkìn tàbí ẹran ẹlẹ́dẹ̀ | Ọbẹ̀ ẹran tí a le sè pẹ̀lú ṣíkìn tàbí ẹlẹ́dẹ̀ | |
Chili con carne | United States (Texas) |
Ẹran màálù | Ọbẹ̀ ẹran tí ó kún fún ẹran màálù, ata àti àwọn ohun èlò mìíràn | |
Cholent | France | Ẹran màálù tàbí ẹran ṣíkìn | Ọbẹ̀ yìí jẹ́ èyí tí wọ́n máa ń sè mọ́júmọ́. Wọ́n sáábà máa ń jẹ ọbẹ̀ yìí pẹ̀lú oúnjẹ Shabbat. Àwọn èròjà rẹ̀ ni ẹran, àlùbọ́sà, ànàmọ́, ẹ̀wà àti barley. Wọ́n gbà pé láti inú hamin ti Sephardic Jews ni wọ́n ti rí i. | |
Chupe Andino | Andes | ẹran ìgbẹ́ | Refers to various stews and soups that are prepared in Ó ń tọ́ka sí àwọn ọbẹ̀ tí wọ́n sè ní ẹkùn Andes Mountains ti ilẹ̀ South America | |
Chupín | Uruguay | Ẹja | Ọbẹ̀ ẹja pẹ̀lú àlùbọ́sà | |
Ciambotta | Italy | Vegetarian | Ọbẹ̀ tó dá lórí àwọn ẹ̀fọ́, ṣùgbọ́n tí ó le ní àwọn èròjà mìíràn | |
Cioppino | United States (San Francisco) |
Ẹja | Ọbẹ̀ ẹja àwọn Italian-American, èyí tí wọ́n máa ń sè pẹ̀lú ẹja tí wọ́n bá sẹ̀sẹ̀ pa | |
Cocido lebaniego | Spain (Cantabria) |
Ẹran ẹlẹ́dẹ̀ àti offal | Ọbẹ̀ yìí ládùn púpọ̀ | |
Cocido madrileño | Spain (Madrid) |
ẹran ẹlẹ́dẹ̀ | Àwọn èròjà rẹ̀ ni chickpea tàbí ẹ̀wà garbanzo, èyí tí ó bá tóbi, tí a mọ̀ sí kabuli. Bẹ́ẹ̀ ni a máa ń da ẹ̀fọ́ mọ́ ọn. | |
Cocido montañés | Spain (Cantabria) |
Ẹlẹ́dẹ̀ àti offal | ọbẹ̀ yìí ni a tún ń pè ní ọbẹ̀ highlander. A máa ń sè é pẹ̀lú white beans àti collard greens (berza). | |
Compote | ẹran ìgbẹ́ | ọbẹ̀ ẹran ìgbẹ́ onírúurú | ||
Coq au vin | France | Ṣíkìn | ọbẹ̀ ṣíkìn | |
Cotriade | France (Brittany) |
Ẹja | Ọbẹ̀ ẹja tí ó jẹ́ onírúurú | |
Cozido/Cocido | Portugal Spain |
Various | Oúnjẹ tí a sè pẹ̀lú onírúurú ẹran àti ẹ̀fọ́; ẹ̀ka kọ̀ọ̀kan ló ní irúfẹ́ oúnjẹ wọn káàkiri Portugal àti Spain | |
Cream stew | Japan | Various | Oúnjẹ àwọn Japanese Yōshoku tí ó kún fún ẹran, bíi ṣíkìn tàbí ẹran ẹlẹ́dẹ̀, tí a dàpọ̀ mọ́ ẹ̀fọ́, àlùbọ́sà, kárọ́ọ̀tì, abbl | |
Daube | France (Provence) |
Ẹran màálù | Ọbẹ̀ tí a sè pẹ̀lú ẹran màálù tí owó rẹ̀ kò wọ́n púpọ̀ pẹ̀lú àwọn ẹ̀fọ́ àti èròjà mìíràn. | |
Dillegrout | United Kingdom (England) |
Fowl | Ọbẹ̀ ẹran ṣíkìn. [3] | |
Dimlama | Uzbekistan | Àgùntàn | Ọbẹ̀ tí a sè pelu àdàlù oríṣi ẹran, ànàmọ́, àlùbọ́sà, ẹ̀fọ́, àti nígbà mìíràn pẹ̀lú èso. | |
Dinuguan | Philippines | Offal | Ọbẹ̀ àwọn Filipino | |
Drokpa Katsa | Tibet | Offal | Ọbẹ̀ tí ó kún fún ìfun ẹran àti iyọ̀ pẹ̀lú àwọn èròjà mìíràn. | |
Escudella i carn d'olla | Spain (Catalonia) |
Sausage | Ọbẹ̀ tí ó kún fún pilota, bẹ́ẹ̀ ni a le lo oríṣi ẹ̀yà ẹran mìíràn | |
Étouffée | United States (Louisiana) |
Seafood | Oúnjẹ àwọn Creole ti Louisiana èyí tí wọ́n sáábà máa ń fi jẹ ìrẹsì. Wọ́n máa ń pè é ní "smothered" ní French. | |
Fabada Asturiana | Spain (Asturias) |
Ẹlẹ́dẹ̀ | A máa ń sè é pẹ̀lú ẹ̀wà funfun àti apá ẹran ẹlẹ́dẹ̀. | |
Fabes con almejas | Spain (Asturias) |
Seafood | A máa ń fi ọbẹ̀ yìí jẹ búrẹ́dì àti àwọn oúnjẹ mìíràn | |
Fahsa | Yemen | Àgùntàn | Ọbẹ̀ tí a sè pẹ̀lú àwọn ẹ̀yà ara ẹran àgùntàn | |
Fårikål | Norway | Ẹran àgùntàn | Ọbẹ̀ ẹran àgùntàn tí ó máa ń ní ata àti àwọn èròjà amún-ọbẹ̀-dùn | |
Fasole cu cârnaţi | Romania | Sausage | ọbẹ̀ tí ó kó ẹ̀wà àti àwọn èròjà mìíràn sínú. | |
Feijoada | Brazil Portugal Uruguay |
Ẹran màálù | Ọbẹ̀ ẹ̀wà pẹ̀lú ẹran màálù tàbí ẹlẹ́dẹ̀ tí a le jẹ pẹ̀lú ẹ̀fọ́. | |
Fesenjān | Iran | Fowl | Ọbẹ̀ ẹran àti ẹja | |
Flaki | Poland | ẹran màálù | Ọbẹ̀ ẹran màálù àti àwọn ohun èròjà oríṣiríṣi | |
Főzelék | Hungary | Vegetarian | Ọbẹ̀ ẹ̀fọ́ tí ó máa ń ki gan tí a máa ń jẹ pẹ̀lú ẹran. | |
Fricot | Canada (Acadia) |
Various | Ọbẹ̀ yìí kún fún ànàmọ́, àlùbọ́sà àti àwọn onírúurú ẹran tí ó bá wà |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Aʿlam, H.; Ramazani, N. (December 15, 1989). "Bāmīā". Encyclopædia Iranica, Vol. III. pp. 656–657.
- ↑ Alikhani, Nasim; Gambacorta, Theresa (2023-06-27). Sofreh: A Contemporary Approach to Classic Persian Cuisine: A Cookbook. Knopf Doubleday Publishing Group. pp. 129–130. ISBN 978-0-593-32075-4. https://books.google.com/books?id=2oCHEAAAQBAJ&pg=PA129.
- ↑ Clarkson, Janet (2010). Soup : a global history. London: Reaktion. pp. 113–114. ISBN 978-1-86189-774-9. OCLC 642290114.