Àwọn ọbẹ̀

Àtòjọ àwọn ọbẹ̀

Àkójọpọ̀ Àwọn ọbẹ̀ lóríṣiríṣi ní àgbáyé.

Orúkọ Àwòrán Orírun Trad­ional protein Àpèjúwe àti àwọn ohun èlò
Gaisburger Marsch Germany
(Swabia)
ẹran màálù oúnjẹ àwọn Swabian tí wọ́n ṣe láti ara ẹran àti ànàmọ́ ṣíṣè àti spätzle.
Galinhada Brazil Fowl ọbẹ̀ ìrẹsì àti ṣíkìn
Garbure France
(Gascony)
ẹran ẹlẹ́dẹ̀ Ọbẹ̀ ham pẹ̀lú cabbage àti àwọn ẹ̀fọ́ mìíràn
Ghapama Armenia Vegetarian Ọbẹ̀ yìí kì í ní ẹran nínú
Gheimeh Iran ọmọ ẹran àgùntàn ọbẹ̀ ẹran àgùntàn gígé nígbà mìíràn ó lè jẹ́ ẹran màálù. Wọ́n sáábà máa ń jẹ ọbẹ̀ yìí pẹ̀lú ìrẹsì funfun.
Ghormeh sabzi Iran Vegetarian (ṣùgbọ́n tí wọ́n máa ń ṣe pẹ̀lú ẹran nígbà mìíràn) Ọbẹ̀ tí a fi egbò àti ẹ̀fọ́ sè
Goat water Montserrat Ewúrẹ́ Oúnjẹ gbogboogbò ti Montserrat èyí tí wọ́n máa ń sè pẹ̀lú ẹran ewúrẹ́ àti ẹ̀fọ́
Goulash Hungary Ẹran màálù Ọbẹ̀ ẹran màálù pẹ̀lú ẹ̀fọ́ àti àwọn èròjà mìíràn
Guatitas Chile
Ecuador
Offal Ọbẹ̀ tí ó jẹ́ pé èròjà rẹ̀ jẹ́ ìfun
Guiso carrero Argentina
Uruguay
Ẹran màálù Ọbẹ̀ ìbílẹ̀ tí a máa ń sè pẹ̀lú ẹran màálù, chorizoh, ẹ̀wà funfun, chickpeas, ànàmọ́, kárọ́ọ̀tì, àlùbọ́sà.
Gumbo United States
(Louisiana)
Seafood àti sausage Ọbẹ̀ tí ó kún fún ata àti àlùbọ́sà
Güveç Turkey ọmọ ẹran àgùntàn Ọbẹ̀ ẹran àti ẹ̀fọ́, èyí tí ó gbajúmọ̀ ní àwọn orílẹ̀-èdè Balkan.
Guyana Pepperpot Guyana Various Ọbẹ̀ ẹran àti ata, a lè lo ẹran ṣíkìn pẹ̀lú
Hachee Netherlands Various Ọbẹ̀ ìbílẹ̀ àwọn Dutch tó dá lórí ẹran gígé, ẹja, tàbí ẹran adìẹ, àti ẹ̀fọ́.
Hamin Iberia Àgùntàn, ẹran màálù, tàbí ṣíkìn Ọbẹ̀ ìbílẹ̀ àwọn Jewish tí wọ́n máa ń jẹ fún Sabbath wọ́n máa ń sè é mọ́jú. Èyí tí a tún mọ̀ sí dafina.
Hasenpfeffer Germany Ẹran ìgbẹ́ Ọbẹ̀ ìbílẹ̀ àwọn German tí wọ́n ṣe láti ara ẹran ehoro.
Hochepot France Ẹran màálù Ọbẹ̀ Flemish tí wọ́n sè láti ara oxtail àti àwọn ẹ̀fọ́
Hoosh United States Ẹran màálù (gbígbẹ) Ọbẹ̀ kíkì tí wọ́n sè pẹ̀lú ẹran màálù
Hot pot China
Taiwan
Mongolia
Various Ọbẹ̀ tí wọ́n sè pẹ̀lú onírúurú ẹran.
Irish stew Ireland Àgùntàn Ọbẹ̀ tí a sè pẹ̀lú ẹran àgùntàn
Islim or patlıcan kebabı Turkey Ẹran àgùntàn Ọbẹ̀ ẹran pẹ̀lú àwọn ata
Istrian stew Croatia Ẹlẹ́dẹ̀ Ọbẹ̀ tí àwọn èròjà rẹ̀ jẹ́ ẹ̀wà, sauerkraut, ànàmọ́, bacon, àti àwọn èròjà mìíràn
Jjigae Korea Various Ọbẹ̀ tí a sè pẹ̀lú àwọn ẹran àti oríṣiríṣi ata.[1]
Jugged hare France
United Kingdom
ẹran ìgbẹ́ Ọbẹ̀ tí a pèèlò pẹ̀lú ẹran ehoro gẹ́gẹ́ bíi èròjà tí ó ṣe kókó
Kadyos, bay, kag langka Philippines Ẹran ẹlẹ́dẹ̀ Pigeon peas, ham hock, àti [[jackfruit] (Garcinia binucao)[2]
Kadyos, manok, kag ubad Philippines Fowl Pigeon peas, [[ṣíkìn], àti ọ̀gẹ̀dẹ̀ [3][4]
Kaldereta Philippines Ẹran ewúrẹ́ Ọbẹ̀ tí èròjà rẹ̀ jẹ́ apá ẹran ewúrẹ́ pẹ̀lú tòmátò àti ẹ̀dọ̀ ewúrẹ́

Nm

Philippines Ẹran màálù ọbẹ̀ ẹran màálù tí a sè pẹ̀lú ẹ̀pà àti àwọn èròjà mìíràn
Karelian hot pot Finland Ẹran màálù àti ẹran ẹlẹ́dẹ̀ Wọ́n máa ń ṣe ọbẹ̀ yìí pẹ̀lú ẹran màálù àti ẹran ẹlẹ́dẹ̀ pẹ̀lú àwọn èròjà mìíràn

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Àdàkọ:In lang Jjigae[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́] at Doosan Encyclopedia
  2. "It's Time You Know about Kadios⁠ beyond KBL". Pepper.ph. Archived from the original on 23 September 2020. Retrieved 8 February 2021. 
  3. "Manok at Kadyos / Purple Chicken With Pigeon Peas". Market Manila. 21 October 2007. Retrieved 8 February 2021. 
  4. "Kadyos Beans". Ark of Taste. Slow Food Foundation for Biodiversity. Retrieved 8 February 2021.