Èdìdí Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà
Èdìdí Ààrẹ Àpapọ̀ Olómìnira ilẹ̀ Nàìjíríà (Seal of the President of the Federal Republic of Nigeria) ni ami-idamo onibise Aare ile Naijiria. O koko je lilo ni 1979 latowo Aare Shehu Shagari ni igba oselu keji to teribomi, o je kikoti latowo awon ijoba ologun larin 1983 titi de 1999. Edidi Aare pada si lilo leyin ti Naijiria pada si oselu ni 1999, o si n je lilo lati gba na lo.
Èdìdí Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà | |
---|---|
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ | |
Ọ̀pá àṣẹ | Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà |
Lílò | 1979 (Current incarnation adopted 1999) |
Crest | On a wreath, Argent and Vert, an eagle displayed gules |
Escutcheon | Blazoned sable a pall wavy argent |
Supporters | Two horses Argent |
Motto | UNITY AND FAITH, PEACE AND PROGRESS |
Use | On documents from the president to Parliament, and as a symbol on presidential vehicles, lecterns, and other places |
Ijuwe
àtúnṣeEdidi Aare ile Naijiria duro lori Ami Opa Ase ile Naijiria. Ami Opa Ase Naijiria ni apata dudu pelu ila fuufun meji ti won pade bi leta Y. Awon wonyi duro fun awon odo meji ti won n san gba Naijiria koja: odò Benue ati odò Ọya. apata dudu duro fun ile didara nigbati awon esin legbe mejeji duro fun iyì. Àṣá duro fun okun, aso ila awo ewe ati funfun lori apata duro fun ogbin ile.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |