Ìjọba ìbílẹ̀ Ọdẹ́dá
Ọdẹ́dá jẹ́ Ìjọba Ìbílẹ̀ àti ìletò kan ní Ìpínlẹ̀ Ògùn, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Olú ilé-iṣẹ́ Ìjọba ìbílẹ̀ yí wà ní A5 highway7°13′00″N 3°31′00″E / 7.21667°N 3.51667°E. Ìjọba ìbílẹ̀ yí ní ibùsọ tí ó 1,560 km² tí àwọn olùgbé ibẹ̀ sì tó 109,449 gẹ́gẹ́ bí étò ìkànìyàn ti ọdún 2006 ṣe fi lọ́ọ́lẹ̀. Ìjọba ìbílẹ̀ yí súnmọ́ Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ pẹ́kípẹ́kí, tí ó sì pààlà pẹ̀lú Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ní ìlú Alọ̀gì.
Ọdẹ́dá | |
---|---|
LGA and town | |
Motto(s): Ọdẹ́dá Gbayì | |
Coordinates: 7°13′N 3°31′E / 7.217°N 3.517°ECoordinates: 7°13′N 3°31′E / 7.217°N 3.517°E | |
Country | Nàìjíríà |
State | Ìpínlẹ̀ Ògùn |
Government | |
• Local Government Chairman and the Head of the Local Government Council | Sẹ̀míù Bọ́lá [1] |
Area | |
• Total | 1,560 km2 (600 sq mi) |
Population (2006 census) | |
• Total | 109,449 |
Time zone | UTC+1 (WAT) |
3-digit postal code prefix | 110 |
ISO 3166 code | NG.OG.OD |
Nọ́mbà ìfiránṣẹ́ (postal code) ìjọba ìbílẹ̀ yí 110.[2]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2019-08-09. Retrieved 2020-06-09.
- ↑ "Post Offices- with map of LGA". NIPOST. Archived from the original on October 7, 2009. Retrieved 2009-10-20..