Ìlú Ọ̀tà
Ìlú Ọ̀tà (tì á tún mọ̀ sí Otta '' ) jẹ́ ílú kán nì Ìpínlé Ogún, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, àtí pé o ní iye àwọn ènìyàn tí wọ́n jẹ́ olùgbéré-jáde tí ó tó 163,783 ń iye. Ọ̀tà ni ó Ìlú tí Ìjọba ìbílẹ̀ Adó-Odò wà. Ọba alaye àti aláṣẹ tí ó wà lórí àga àṣẹ lọ́wọ́ lọ́wọ́ yí ni Ọ́lọ̀tá tí Ọ́tá Ọba Adéyẹmí AbdulKabir Ọba lánlẹ́gẹ́ . Gẹ́gẹ́ bí ìtàn ti ṣe fi lélẹ̀, Ọ́ta jẹ́ olú ílù àwọ́ń Àwórì tí wọ́n jẹ́ ẹ̀yà kan nílẹ̀ Yorùbá [1]
Nínú akọsílẹ̀ ọ́dùń 1999, Ọ̀tà ni ó wà nípò kẹ́ta ní Ìpínlẹ̀ Ògùn tí ó ní ilé-iṣẹ́ tí ó pọ̀ jùlọ. [2] Ọjà ńlá kan ati oju ọnà márosẹ̀ tí lọ láti Ìpínlẹ̀ Èkó lọ sí ìlú Abẹ́òkúta, ìlú Ọ̀tà yí kan náà ni Ilé-iṣẹ́ ohun ọ̀gbìn Ààrẹ tẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà nígbà kan ri, Ààrẹ Olúṣẹ́gun Ọbásanjọ tí a mọ̀ sí Ọ̀tà Farm. Ba kan náà ni ilé-ìjọsìn ti church Winners 'Chapel tí ọ̀gbẹ́ni David Oyèdépò jẹ́ olùdásílẹ̀ r.
Ítáń-ákọ́ọ̀lẹ̀
àtúnṣeÌtàn àtẹnudẹ́nu àwọn Yorùbá sọ wípé àwọn Àwórì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọ Ọ́lọ́fin, Ọsọ́lọ̀ àti Eleidi Atalabi ni wọ́n ta ìlú Ọ̀tà dó leyin tí wọ́n kúrò láti apá ìhà Gúsù Ìṣẹri. [3] Lẹ́yìn tí ìlú Ọ̀tà dàgbàsókè tán, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí ní jẹ Ọba aládé tí ìnagijẹ rẹ̀ sì ń jẹ́ Ọláọ́tà ti Ọ̀tà tí ó sì ń ìṣèjọba lórí àwọn ìlú amọ́nà abẹ́ wọn káàkiri. Ọ̀pá àṣẹ Ọba naa ni wọ́n gbà wá láti ìlú Ilé-Ifẹ̀. Ìlú Ọ̀tà di ìlú ńlá tí àwọn ilé-iṣẹ́ ńlá ńlá àti kéréje-kéréje ní Ìpínlẹ̀ Ògùn [4] Ní ọdún 1842, látàrí ìdàgbàsókè ikẹ̀ Ẹ̀gbá, èyí mú kí ìlú Ọ̀tà wà ní abè ìṣèjọba ìlú Abẹ́òkúta. Síbẹ̀ Ọ̀tà da dúró láàrín àwọn ìlú tí ó wà lábẹ́ ìṣèjọba ilẹ̀ Ẹ̀gbá, tí ó sì wà láàrín àwọn ìlú ó lààmì-laaka láàrín àwọn ìlú ilẹ̀ Àwórì . [1] [5]
Ní àsìkò ọdún 1900, ètò ìṣèjọba àti ìṣàkóso ní ìlànà ẹ̀tọ́ ni ó jẹ́ wípé àwọn Ògbóni ni wọ́n ṣàmójútó rẹ̀. Ẹgbẹ́ Ògbóni yí ni wọ́n ń ṣòfin tí wọ́n sì ń mú òfin naa ṣẹ lórí ẹnikẹ́ni tí ó bá ra 9fin náà. Dada ilé-iṣẹ́ ọlọ́pàá sílẹ̀ẹ̀ ní àsìkò ọdún 1903 ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti Ma gbé òfin ro lábẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ tàbí Ìpínlẹ̀ ni ó sọ iṣẹ́ àwọn Ògbóni di yẹ̀bù yẹ́bù tí wọn kò sì ní agbára kan kan láti ṣiṣẹ́ mọ́ nígbà t yóò fi di nkan bí ọdún 1950. [6]
Gbígbé ìlànà òfin owó-orí kalẹ̀ lábẹ́ ìjọba àpapọ̀ ni ó da rúgúdù àti rògbòdìyàn sílẹ̀ẹ̀ ní ìlú Ọ̀tà ní ọdún 1954. Látàrí fàá-kája tí àwọn ará ìlú àti ìjọba ń fà yí ni ó mú kí ìjọba tún gbé ofin owó-orí mìíràn jáde ní ọjọ́ Kẹrin oṣù Kejì tí àwọn ẹgbẹ́ Ayépéjú Ẹgbè olówó-orí ti ìlú Ọ̀tà sì dide fẹ̀hónú wọn hàn tako ìlànà sísan owó-orí náà. Ifẹ̀hónú hàn náà di iṣu ata yán an yàn an, de bi tí wọ́n ń ba àwọn nkan olówó iyebíye jẹ́ láàrín ìlú. Orúkọ tí wọ́n fún ifẹ̀hónú hàn tí ó di ìjà gboro yí ni Pónpó Ayépéjú, ina gboro yí ni ó jẹ́ wípé àwọn ọlọ́pàá ni wọ́n wa gbo dẹ́kun fun. Lẹ́yìn rògbòdìyàn yí ni àwọn ìgbìmọ̀ ẹgbẹ́ẹ́ ìṣòkan ilẹ̀ Àwórì ya Ọba Timothy Fádìnà nílò gẹ́gẹ́ bí Ọba ní ọjọ́ọ́ Kọkànlá oṣù Karùn-ún ọdún 1954. [6] Ìlú Ọ̀tà bẹ̀rẹ̀ sí ń gbẹ̀rú si látàrí iṣẹ́ takun-takun tí gómìnà tẹ́lẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ Ògùn Olóyè Bísí Ọnàbánjọ gbé láti jẹ́ kí ìjọba Ìpínlẹ̀ náà ó dòwò po pelu àwọn ẹgbẹ́ onílé iṣẹ́ ńlá ńlá àti kéréje-kéréje ti orílé-èdè Nàìjíríà wọ ìlú Ọ̀tà wá.. [2]
Ètò Ẹ̀kọ́
àtúnṣeTraditionally, Áwọ̀ń ílẹ́ íwe díẹ́ lowá ní ílù Ótá ti áwọ̀ń ẹ́lẹ́sìń ígbágbọ̀ jẹ́ olùgbọ́wọ̀ rẹ́ . Awọ̀n àdùgbo ti awọ̀ń ẹ́lẹ́sìń ímale wa ,woń da íle iwe kan ti ìjọ̀ Ansar-Ud-Deen dáàrì rẹ́. Àwọ̀ń íle íwe ípìńlẹ́ bẹ́rẹ̀ nì odùń 1970s átì áwọ̀ń íle ìwe àdáńì ńì agbegbe náá . Iganmode Grammar School jẹ́ ìle ìwe tì o tì pẹ́ , tì wọ̀ń sí dá kálẹ́ ńì ọ́dùń 1960 . Ńìńù awọ̀ń Ile iwe igbana A nsar-Ud-deen Comprehensive College, Bells Comprehensive Secondary School átì Faith Academy Secondary School.[7]
Íle íwe gígá meji lowá ńì Ọ́tá : Covenant University átì Bells University of Technology. Átì ile ìwe àdańì kor iyẹń polytechnic: Allover central polytechnic. íle iwe ti orí le de Nìjíriá iyẹ́ń ile-iwe Orìń fùń awọ̀ń àṣọ̀bode Ori omì ,owá Ni ilu Ọ́tá.
Áje
àtúnṣeÁwọ̀ń ápàkáń tì ílù ńáà jẹ́ gábà lorì nípásẹ́ awọ̀ń íle-íṣẹ́ pẹ́lù Eko - Abeokuta rd ati Idi-Oroko rd. Bíbẹrẹ nì íbẹ́rẹ̀ ọ́dùń 1970, ọ́pọ̀lọ́pọ̀ áwọ̀ń ìle-íṣẹ́ bẹ́rẹ̀ sí kọ̀ áwọ̀ń íle-íṣẹ́ lọ̀pọ̀ló ní Ọ́tá ní àpákàń ńítorì pe o kere pùpọ̀ jù awọ̀ń íle-íṣẹ́ ile-iṣẹ ni eko. Awọ̀ń isọ́wọ̀ pẹ́lù awọ̀ń ohùń elo ni Ọ́tá pẹ́lù:
- Farmex Meyer Limited
- Awọn Breweries ti Nigeria
- De United Foods Industries Limited
- Awọn Oogun Alailẹgbẹ [9]
- Intercontinental Distillers Opin.
- Nkan iṣelọpọ Honda (Nigeria), Ltd
Onírúrù eńìyáń
àtúnṣeÁwọ̀ń ọ́mọ̀ ilu ní o wa borí Yorùbá ti áwọ̀ń Áworì dialect ẹgbẹ. Wọ́ń tọ̀pá ídìle wọ̀ń látì Ile- ífẹ̀ wọn si ka Iganmode bi baba nla wọn. Áworì míìráń wà nì Ípìńlẹ́ Eko Ati agbegbe ẹ́.
Íṣẹ̀ anọ́kọ̀ Ti awọ̀ń olùgbe Ọ́tá jẹ́ íṣowo ati ogbin. Isunmọ ilu si Eko atí osùń mọ̀ sí ílù áàlá tì ídìroko tí yorì sí ídàsìlẹ̀ aáwọ̀ń ọ̀já ń là mejì: Ọ́jà Kayero ni Sáńgo átì Ọ́jà Ọ́bà TT Dádà nì opoponá Ídìroko. Àwọ̀ń ọ̀já wọ́ńyì tobì pùpọ̀ debì pe wọ̀ń parapọ̀ papọ , atì pe wọ́ń tọ̀kà sì diẹ síì bí Ọ́jà Sańgo-Ọ̀tà-Ota. [10]
Rogbodìyán láárìn Áworì átì olùgbe Owù
àtúnṣeỌ́pọ̀lọ́pọ̀ árìjíyáń tì wá láàrìń Owù átì awọ̀ń olùgbẹ́ Áworì tì ágbegbe náà ńì oṣù Kẹ́rìń , ọ́dùń 2008, áwọ̀ń rogbodìyáń ìyà-ipa tì o kere jù eníyáń mẹfá kù ńì ígbátì Áworì átì Owù já lorì Olowù tí Owù tì fí Ọ́bá káń sorì íle Àworì. Áwọ̀ń bálẹ̀ Ípìńlẹ́ Ogùń , Gbenga Daniel, so a dusk-to-owurọ curfew ni Ado-Odo / Ota Ọ́tá àgbegbe ijọ̀bà agbegbe .
Wo eyi náà
àtúnṣe- Ota Chiefs Chiefs
Awọ̀ń itọkasi
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 P.C. Lloyd (1962). Yoruba Land Law. Oxford University Press. p. 225.
- ↑ 2.0 2.1 Ruhollah Ajibola Salako (1999). Ota: The Biography of the Foremost Awori Town. Penink & Co. p. 15.
- ↑ Ruhollah Ajibola Salako (1999). Ota: The Biography of the Foremost Awori Town. Penink & Co. p. 14.
- ↑ Robert Smith (1969). Kingdoms of the Yoruba. Methuen & Co.
- ↑ Robert Smith (1969). Kingdoms of the Yoruba. Methuen & Co. p. 166.
- ↑ 6.0 6.1 Ruhollah Ajibola Salako (1999). Ota: The Biography of the Foremost Awori Town. Penink & Co. p. 23.
- ↑ Ruhollah Ajibola Salako (1999). Ota: The Biography of the Foremost Awori Town. Penink & Co. pp. 16–17.
- ↑ Ruhollah Ajibola Salako (1999). Ota: The Biography of the Foremost Awori Town. Penink & Co. p. 21.
- ↑ "Unique Pharmaceuticals Official Website". Archived from the original on 2020-08-11. Retrieved 2020-12-30.
- ↑ Ruhollah Ajibola Salako (1999). Ota: The Biography of the Foremost Awori Town. Penink & Co. p. 16.