Ìsẹ́yìn
Ìsẹ́yìn jẹ́ ìlú kan tó wà ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ní Nàìjíríà. Tí a lè It wí pé ó wà ní apá Àríwá Ìbàdàn. Ìlú náà ni ènìyàn bí i 236,000, gẹ́gẹ́ bí United Nations ṣe sọ ní 2005, tí àwọn ènìyàn yìí di 362,990 ní ọdún 2011,[1] [2] Ìsẹ́yìn jẹ́ ibí tó jẹ́ wí pé a lè dé ibí tí a bá gba ọ̀nà Ìbàdàn, Ọ̀yọ́, Abẹ́òkúta àti Ògbómọ̀sọ. Ìlú náà ni ilẹ̀ tó fẹ̀, tó ṣe é fi ṣe ilé-òwò àti dá oko, ilé-ìwé fún àǹfààní ní àti àyíká ìlú náà. Orúkọ ọba tí ó jẹ́ ní Isẹ́yìn ni " Àsẹ́yìn Ìlú Ìsẹ́yìn". Àwọn ilé-ìwé pọ̀ ní Ìsẹ́yìn, lára wọn ni Ládòkè Akíntólá, Politẹ́kíníkì bí SAF Politẹ́kíníkì, Ilé-ìwé sẹ́kọ́ndárí bí Kelani Kọlẹ̀jì Ìsẹ́yìn, Greater Love Model àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Tó wà ní àkọsílẹ̀ wí pé àwọn ilé-ìwé yìí ń ṣe dáadáa ní àwọn ìdánwò bí WASSCE & SSCE.
Ìsẹ́yìn | |
---|---|
Ilu | |
Nickname(s): Ilu Aso Oke | |
Orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Ipinle | Oyo |
Agbegbe Ijoba Ibile | Iseyin |
Population | |
• Total | 256,926 |
Website | http://www.iseyinland.com |
Iseyin Iseyin-Okeogun | |
---|---|
LGA and town | |
Nickname(s): Iseyin oro, oro ọmọ ebedi mọkọ | |
Coordinates: 7°58′N 3°36′E / 7.967°N 3.600°E | |
Country | Nigeria |
State | Oyo State |
Government | |
• Local Government Chairman and the Head of the Local Government Council | Muftau Osuolale (PDP) |
Area | |
• Total | 548 sq mi (1,419 km2) |
Time zone | UTC+1 (WAT) |
Climate | Aw |
Àwọn ìlúmọ̀ọ́ká tó wá láti Ìsẹ́yìn
àtúnṣeDíẹ̀ nínú àwọn ìlúmọ̀ọ́ká tó wá láti Ìsẹ́yìn ni:
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ National Population Commission of Nigeria (web)
- ↑ Adewuyi, Kehinde; Adeyemo; Adejumo (December 2018). "Use of GIS in production of soil series map in Oyo State, southwestern Nigeria". International Research Journal of Earth Sciences 6 (12): 12–21. ISSN 2321-2527. http://www.isca.me/EARTH_SCI/Archive/v6/i12/2.ISCA-IRJES-2018-019.pdf.