Òkè Olúmọ
Òkè Olúmọ ni òkè kan tí nó wà ní ilẹ̀ Ẹ̀gbá ìlú Abẹ́òkúta tí ó jẹ́ olú ìlú Ìpínlẹ̀ Ògùn ní apá ìwọ̀ Oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà. Òkè Olúmọ jẹ́ ibìsálà fún àwọn ará Abẹ́òkúta ní àsìkò ogun abẹ́lé ní àsìkò 19th century. Wọ́n sì ń bọ òkè náà gẹ́gẹ́ bí Òrìṣà tí wọ́n sì ń bọọ́ pẹ̀lú oríṣríṣi ẹbọ.[1]
Àbẹ̀wò sí òkè Olúmọ
àtúnṣeÒkè Olúmọ jẹ́ ọ̀kan pàtàkì nínú àwọn òkè gbajúmọ̀ tí àwọn ènìyàn ma ń lọ bẹ̀wò láti gbafẹ́ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[2][3]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Jimoh Babatunde (August 17, 2012). "Olumo Rock: Egbas' shelter, fortress". Nigeria: Vanguard. http://www.vanguardngr.com/2012/08/olumo-rock-egbas-shelter-fortress/. Retrieved June 3, 2014.
- ↑ Ayodeji Ayodele (14 May 2014). "Olumo Rock:An American tourist destination". Nigerian Tribune. http://tribune.com.ng/tourism/item/5144-olumo-rock-an-african-tourist-destination/5144-olumo-rock-an-african-tourist-destination. Retrieved June 3, 2014.
- ↑ Kola Tubosun (16 April 2014). "Abeokuta's Living History". KTravula.com. Archived from the original on 30 June 2019. https://web.archive.org/web/20190630130114/http://www.ktravula.com/2014/04/abeokutas-living-history/.