People's Democratic Party
Ẹgbẹ Oṣelu
(Àtúnjúwe láti Ẹgbẹ́ Olóṣèlúaráìlú àwọn Aráàlù (Nàìjíríà))
Peoples Democratic Party [PDP] (Ẹgbẹ́ Dẹmokrátíkì àwọn Aráàlú) jẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú alátakò ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Wọ́n dá ẹgbẹ́ òṣèlú yìí sílẹ̀ lọ́dún 1998.[1] Àwọn ni ọmọ ẹgbẹ́ wọn ṣe ìjọba àpapọ̀ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà títí di ọdún 2015 kí ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress tó gbàjọba àpapọ̀ lọ́wọ́ wọn. Ààrẹ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà mẹ́ta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀; Olúṣẹ́gun Ọbásanjọ́, Umaru Musa Yar'Adua àti Goodluck Jonathan ni ẹgbẹ́ yìí jẹ kí ẹgbẹ́ APC tó dà wọ́n lágbo nù lọ́dún 2015, tí Ààrẹ Muhammadu Buhari tí ẹgbẹ́ APC fi wọlé gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ.[2]
Peoples Democratic Party | |
---|---|
Chairman | Uche Secondus |
Akọ̀wé Àgbà | Abubakar Kawu Baraje |
Ìdásílẹ̀ | 1998 |
Ibùjúkòó | Wadata Plaza, Michael Okpara Way, Wuse, Abuja |
Ọ̀rọ̀àbá | Moderate |
Official colours | Green, white, red |
Ibiìtakùn | |
PDP, INEC PDP, Yar' adua 2007 | |
Ìṣèlú ilẹ̀ Nigeria |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "People’s Democratic Party (PDP) - History, Objectives, & Facts". Encyclopedia Britannica. 2002-09-27. Retrieved 2023-06-12.
- ↑ "PDP (People's Democratic Party)". BBC News Pidgin. 2023-06-02. Retrieved 2023-06-12.