Ọlágúnsóyè Oyinlọlá

Olóṣèlú

Ọlágúnsóyè Oyinlọlá (ojoibi February 3, 1951) je omo ologun to tifeyinti ati oloselu omo ile Naijiria. Ó jẹ́ alámóójútó ológun fún Ìpínlẹ̀ Èkó láti 1993 de 1996. Ní ìgbà òṣèlú ẹ̀ẹ̀kejì, wọ́n dìbò yàn bí Gomina Ipinle Osun lati 29 May, 2003 de 26 November 2010[1] nigbati ile-ejo fagile idiboyan re sipo fun igba keji gege bi gomina ninu idiboyan 2007.

Ọlagunsoye Oyinlọla
Olagunsoye Oyinlola (left) with Femi Fani-Kayode at a reception in 2007
Administrator of Lagos State
In office
December 1993 – August 1996
AsíwájúMichael Otedola
Arọ́pòBuba Marwa
Governor of Osun State
In office
May 2003 – 26 November 2010
AsíwájúAdebisi Akande
Arọ́pòRauf Aregbesola
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbíFebruary 3, 1951
Okuku, Odo Ọtin LGA, Ọṣun State
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPDP



Ìkìlọ̀: Bọ́tìnì ìtò àkọ́kọ́ṣe "Ọlágúnsóyè, Oyinlọlá" dípò Bọ́tìnì ìtò àkọ́kọ́ṣe "Oyinlola Olagunsoye" tẹ́lẹ̀.