77 Bullets
77 Bullets | |
---|---|
Adarí | Adebayo Tijani |
Olùgbékalẹ̀ | Mercy Aigbe |
Àwọn òṣèré | Temitope Solaja, Ibrahim Yekini and Eniola Ajao |
Déètì àgbéjáde | 2019 |
Orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Èdè | Yoruba |
77 Bullet jẹ́ fíimù ilẹ̀ Nàìjíríà ti ọdún 2019, tí Mercy Aigbe gbé jáde, tí olùdarí rẹ̀ sì jẹ́ Adebayo Tijani.[1][2][3][4]
Ó jẹ́ fíìmù ajẹ́mọ́-ìṣẹ̀lè-tó -le, tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ gbajúmọ̀ òṣèré bí iTemitope Solaja, Ibrahim Yekini àti Eniola Ajao kópa nínú rẹ̀.[5] [6]
Ìsọníṣókí
àtúnṣeFíìmù náà sọ ìtàn ọlọ́ṣà kan tí kò láàánú, tó sì ní ìhámọ́ra oògun tó fi ń ba àwọn aráàlú lẹ́rù, tó sì ń ṣẹ̀rù bà wọ́n. Nígbẹ̀yìn gbẹ́yín, ọwọ́ tẹ̀ ẹ́. Fíìmù náà lọ́ bákan bákan nígbà tí ọ̀dáràn yìí fojú kan ilé-ẹjọ́ tí ìkejì rẹ̀ sì jẹ́ adájọ ní ilé-ẹjọ́ náà.[7][8]
Ìṣàfihàn
àtúnṣeÌṣàfihàn àkọ́kọ́ fíìmù yìí wáyé lórí YouTube ní 20 December, ọdún 2019.
Àwọn akópa
àtúnṣe- Mercy Aigbe
- Temitope Solaja
- Ibrahim Yekini
- Eniola Ajao
- Titi Osinowo
- Bimbo Afolayan
- Eniola Afeez
- Taiwo Ibikunle
- Adeniyi Johnson
- Yinka Quadri
- ↑ Bada, Gbenga (2019-12-19). "Mercy Aigbe completes work new film, ‘77 Bullets’". Pulse Nigeria. Retrieved 2022-08-03.
- ↑ "Mercy Aigbe announces new movie, 77 Bullets". The Nation Newspaper (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-01-29. Retrieved 2022-08-03.
- ↑ Ogala, George (2020-06-20). "Movie Review: Mercy Aigbe’s ‘77 Bullets’: All hype, no substance". Premium Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-03.
- ↑ "Movie Review: Mercy Aigbe’s ‘77 Bullets’: All hype, no substance". ENigeria Newspaper (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-06-20. Archived from the original on 2022-08-03. Retrieved 2022-08-03.
- ↑ Empty citation (help)