Temitope Solaja
It has been suggested that this article be merged with Àdàkọ:Pagelist. (Discuss) |
Temitope Solaja | |
---|---|
Fáìlì:Temitope Solaja.jpg | |
Orúkọ míràn | Star Girl[1] |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Tai Solarin University of Education |
Iṣẹ́ | Film actress |
Temitope Solaja Listen jẹ́ òṣèrébìnrin ilẹ̀ Nàìjíríà, òǹkọ̀tàn àti aṣagbátẹrù fíìmù.
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeTemitope Solaja jẹ́ ọmọ àkọ́bi àwọn òbí rẹ̀, ìlú Sagamu ní Ìpínlẹ̀ Ògùn ló sì ti wá. Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè bachelor's degree nínú ìmọ̀ Mass communication láti Tai Solarin University of Education.[2]
Iṣẹ́ tó yàn láàyò
àtúnṣeNí ọdún 2008, Solaja gba iṣẹ́ eré-ṣíṣe àkọ́kọ́ rẹ̀, láti kópa nínú fíìmù Bamitale. Solaja di gbajúmọ̀ òṣèré nígbà tí ó kópa nínú fíìmù tí Sola Akintunde Lagata gbé jáde tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Opolo, ní ọdún 2019.[3] Ní ọdún 2015, ó kọ fíìmù rẹ̀ tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Aruga, ó sì gbé e jáde. Àwọn àgbà òṣèré bí i Antar Laniyan, àti Sunkanmi Omobolanle ló kópa nínú fíìmù náà.[4]
Ní ọdún 2017, wọ́n yàn án fún òṣèrébìnrin tó dára jù ní ayẹyẹ Best of Nollywood Awards ti ọdún 2017.[5]
Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀
àtúnṣe- Bamitale
- Opolo
- Idemu Ojo kan
- The Antique
- Adajo Aiye
- Kudi Klepto
- Bella
- Firepemi
- Aruga
- Darasimi
- Awelewa
- Orente
- Juba[6]
- 77 Bullets[7]
Àtòjọ àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀
àtúnṣeỌdún | Àmì-ẹ̀yẹ | Ìsọ̀rí | Iṣẹ́ | Èsì | Ìtọ́ka |
---|---|---|---|---|---|
2015 | Best of Nollywood Awards | Best Supporting Actress (Yoruba) | Bella | Wọ́n pèé | [8][9] |
2017 | Best Actress in a Leading Role (Yoruba) | Ashabi Akata | Wọ́n pèé |
Àwọn ìtọkasí
àtúnṣe- ↑ "ICYMI: I can date, marry a fan –Temitope Solaja - Punch Newspapers". Punch Newspapers. February 22, 2020. Retrieved August 3, 2022.
- ↑ Oluwafunmilayo, Akinpelu (September 14, 2018). "Actress Temitope Solaja expresses gratitude as she buys new car". Legit.ng - Nigeria news. Retrieved August 3, 2022.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "4 top up and coming Yoruba actresses: Temitope Solaj". Encomium Magazine. August 3, 2022. Retrieved August 3, 2022.
- ↑ Bada, Gbenga (May 30, 2015). "Watch Antar Laniyan, Biodun Okeowo, others in new Yoruba movie". Pulse Nigeria. Archived from the original on August 3, 2022. Retrieved August 3, 2022.
- ↑ Augoye, Jayne (September 12, 2017). "Omotola Jalade-Ekeinde, Mercy Aigbe, Alexx Ekubo top BON Awards nominee list". Premium Times Nigeria. Retrieved August 3, 2022.
- ↑ THISDAYLIVE, Home - (October 16, 2020). "Funmiade Bank-Anthony Explains new Movie – THISDAYLIVE". THISDAYLIVE – Truth and Reason. Archived from the original on August 3, 2022. Retrieved August 3, 2022.
- ↑ Bada, Gbenga (December 19, 2019). "Mercy Aigbe completes work new film, ‘77 Bullets’". Pulse Nigeria. Retrieved August 3, 2022.
- ↑ Lawal, Fuad (December 14, 2015). "See full list of winners". Pulse Nigeria. Retrieved August 3, 2022.
- ↑ Izuzu, Chibumga (October 26, 2015). "Nse Ikpe-Etim, Stephanie Linus, Hilda Dokubo, Ini Edo, Iyabo Ojo battle for 'Best Actress'". Pulse Nigeria. Archived from the original on August 3, 2022. Retrieved August 3, 2022.