A Place in the Stars
A Place in the Stars jẹ́ fíìmù orílẹ̀-èdẹ̀ Nàìjíríà ti ọdún 2014, tó jẹ́ mọ́ ìwà-ọ̀daràn. Ita Hozaife ló kọ fíìmù yìí, tí J. K. Amalou, sì ṣe àgbéjáde rè, Steve Gukas sì ni olùarí eré náà. Lára àwọn akópa inú fíìmù yìí ni Gideon Okeke, Segun Arinze, Matilda Obaseki, Yemi Blaq, Femi Branch àti Dejumo Lewis.[3][4][5] Ìwúnilórí láti gbé fíìmu ̀ yìí jáde wá látara Professor Dora Akunyili (olóògbé), gẹ́gẹ́ bí i Director General fún àjọ tó ń rí sí ìmójútó àti ìdarí oúnjẹ àti oògùn, ìyẹn (NAFDAC).[6]
A Place in the Stars | |
---|---|
Adarí | Steve Gukas |
Olùgbékalẹ̀ | Steve Gukas Nosa Obayuwana |
Òǹkọ̀wé | Ita Hozaife J. K. Amalou |
Àwọn òṣèré | |
Orin | George Kallis |
Ìyàwòrán sinimá | Harald Beeker John L. Demps Jr. Manu Lapière |
Olóòtú | Antonio Rui Ribeiro |
Ilé-iṣẹ́ fíìmù | Natives Filmworks Jungle FilmWorks |
Olùpín | Silverbird Film Distribution |
Déètì àgbéjáde |
|
Àkókò | 108 minutes |
Orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Èdè | English |
Ìnáwó | ₦160 million (est)[1][2] |
Àhunpọ̀ ìtàn
àtúnṣeỌdún 2006 ni wọ́n fi sọrí fíìmù yìí,[7] ó sì sọ ìtàn Kim Dakim (Gideon Okeke), tó jẹ́ agbẹjọ́rò tó ní ìròyìn nípa ìgbé oògùn ẹ̀bùrú kiri lọ́nà àìtọ́, tí ó sì wà nípò láti rí ọ̀pọllọpọ̀ owó bí kò bá gbé ìròyìn yìí jáde sí gbangba. Àmọ́ ṣáá, Diokpa Okonkwo (Segun Arinze) ṣe tán láti pa ẹnikẹ́ni tó bá máa dè é lọ́nà. Kim sì ń jìjàkadì pẹ̀lú ẹ̀rí-ọkàn rẹ̀ àti gbogbo ìwà-ọmọlúàbí tó mú ní òkúnkúndùn.
Àwọn akópa
àtúnṣe- Gideon Okeke bí i Kim Dakim
- Segun Arinze bí i Diokpa Okonkwo
- Dejumo Lewis bí i Pa Dakim
- Matilda Obaseki bí i Tari
- Femi Branch bí i Young Pa Dakim
- Yemi Blaq bí i James
- Julian Mcdowell bí i MD Rasco Mining
- Armajit Deu bí i Veejay
- Amaka Mgbor bí i Vickie
- Ladi Alpha bí i Simi Dakim
- Zubairu J. Attah bí i Charles Coker
- Lantana Ahmed bí i Ngo Simi
Ìgbóríyìn fún
àtúnṣeWọ́n yan fíìmù A Place in the Stars fún àmì-ẹ̀yẹ mọ́kànlá ní 2015 Africa Magic Viewers Choice Awards, ó sì gba àmì-ẹ̀yẹ "Best Drama Film".[8]
Award | Category | Recipients and nominees | Result |
---|---|---|---|
Multichoice (2015 Africa Magic Viewers Choice Awards)[9][10] |
Best Movie of 2014 | Steve Gukas | Wọ́n pèé |
Best Movie (Drama) | Steve Gukas | Gbàá | |
Best Movie Director | Steve Gukas | Wọ́n pèé | |
Best Supporting Actor | Segun Arinze | Wọ́n pèé | |
Best Actress in a Drama | Amaka Mgbor | Wọ́n pèé | |
Best Actor in a Drama | Gideon Okeke | Wọ́n pèé | |
Best Cinematography | John Demps, Harald Beeker & Manuel Lapiere | Wọ́n pèé | |
Best Make-Up Artist | Chinwem Elevoh & Sandra Udoewah | Wọ́n pèé | |
Best Sound Editing | Susan Penington | Wọ́n pèé | |
Best Video Editing | Antonio Rui Ribeiro | Wọ́n pèé | |
Best Drama Writer | Ita Hozaife, J.K. Amalou | Wọ́n pèé |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Oniwura, Bobola (August 2014). "First Look At Steve Gukas's "A Place In The Stars" Movie As Nollywood Reaches For The Stars – Bobola Oniwura". omojuwa.com. Retrieved 14 September 2014.
- ↑ Offiong, Adie Vanessa (23 August 2014). "When Nollywood saw 'A Place in the Stars'". Weekly Trust NG. Archived from the original on 12 September 2014. Retrieved 14 September 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Native Filmworks unveil 'A Place in the Stars'". City Voice Nigeria. 25 August 2014. Archived from the original on 15 September 2014. Retrieved 14 September 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ O, Segun (24 August 2014). "Movie Trailer: "A Place In The Stars" Starring Segun Arinze, Gideon Okeke, Matilda Obaseki, Femi Branch". 36NG.com. Archived from the original on 3 March 2016. Retrieved 14 September 2014.
- ↑ "Gideon Okeke, Segun Arinze star in "A Place in the Stars"". TVC News. Archived from the original on 29 August 2014. Retrieved 14 September 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedNEWSWATCH
- ↑ Dike, Ada (29 August 2014). "Day Nigerians gathered to catch a glimpse of 'A Place In The Stars'". NewsWatch NG. My Daily NewsWatch. Archived from the original on 14 September 2014. Retrieved 14 September 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Africa Magic Viewers' Choice Awards 2015 nominees list out". Ghana Web. 12 December 2014. Retrieved 23 December 2014.
- ↑ "List Of The 2015 Africa Magic Viewers' Choice Awards (AMVCAs) Nominees". DStv. StarGist. 13 December 2014. Retrieved 7 February 2015.
- ↑ "AMVCA winners announced". Archived from the original on 17 April 2015. Retrieved 9 March 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)