Abula (ọbẹ̀)
Ìkan lára àwọn ọbẹ̀ ilẹ̀ Yorùbá
Àbùlà jẹ ọ̀kan lára ọbẹ̀ àwọn Yorùbá ní Ìwọ̀ Oòrùn Nàìjíríà. [1] Wọ́n ma ń sábà jẹ ọbẹ̀ náà pẹ̀lú Amala, ṣugbọn ó sé fi jẹ àwọn ounjẹ òkèlè miiran. Àdàlù oríṣi ọbẹ̀ ni Abula túmọ̀ sí, ṣùgbọ́n ṣùgbọ́n ó ma ún sábà túmọ̀ sí àdàlù gbegiri (ọbẹ̀ ẹ̀wà), Ewedu àti ọbẹ̀ ata. [2]
Wọ́n má ń ká àbùlà si ọbẹ̀ aládùn kò sì ún ṣe ọbẹ̀ tí wón dédé sẹ̀. Ṣíṣe rè ma ún gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ akitiyan àti àkókò. Àwọn Yoruba ní ìwọ̀ oòrùn Nàìjíríà ní o ma ún sábà ṣe ọbẹ̀ yìí, pàá pàá jùlọ, àwọn èèyàn Ọ̀yọ́ àti Ogbómọ̀ṣọ́.[3]
Wo eyi naa
àtúnṣeAwọn itọkasi
àtúnṣe- ↑ "Amala and Abula". Nigerian Tribune. 2018-02-10. Archived from the original on 2019-04-27.
- ↑ "Best Nigerian Recipes for this weekend - Abula". The Nation. 2017-10-20.
- ↑ "Ogbomoso Ajilete group celebrates Amala, Gbegiri Day". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-08-29. Retrieved 2022-02-26.