Ògbómọ̀sọ́
Ilu ni Naijiria
Ògbómọ̀sọ́ jẹ́ ìlú ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ní apá ìwò-oòrùn oriĺè-èdè Nàìjíríà. A dá ìlú Ògbómọ̀sọ́ sílẹ̀ ní 17th Century.[2] Àpapọ̀ iye àwọn ènìyàn tí ó wà níbè gẹ́gẹ́ bi ètò ìkànìyàn ọdún 2006 se sọ jẹ́ 645,000.[3] Yorùbá pó́ńbélé ni ọ̀pọ̀ àwọn òlùgbé Ògbómọ̀sọ́. Iṣẹ́ àgbẹ̀ iṣu, gbágùúdá, àgbàdo àti ewé sìgá jẹ́ lára àwọn iṣẹ́ tó gbajúmọ̀ jùlo ni Ògbómọ̀sọ́.[4]
Ogbomosho Ògbómọ̀ṣọ́ | |
---|---|
Metropolis | |
Ladoke Akintola University of Technology | |
Nickname(s): Mosh Town | |
Coordinates: 8°08′N 4°15′E / 8.133°N 4.250°ECoordinates: 8°08′N 4°15′E / 8.133°N 4.250°E | |
Country | Nàìjíríà |
State | Oyo State |
Elevation | 347 m (1,138 ft) |
Population | |
• Urban | 454,690 (2,006 census) 702,550 (est. 2,021) |
• Urban density | 2,110/km2 (5,500/sq mi) |
• Metro | 2,000,000 |
Time zone | UTC+1 (WAT (UTC+1)) |
Climate | Aw |
National language | Yorùbá |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Oyo (State, Nigeria)". population.de. Retrieved 25 July 2016.
- ↑ Empty citation (help)
- ↑ Empty citation (help)
- ↑ "Ogbomosho". Columbia Encyclopedia (5th ed.). Columbia University Press. 1993. pp. 1997. http://columbia.thefreedictionary.com/Ogbomosho. Retrieved 2007-04-01.