Afeez Oyetoro

(Àtúnjúwe láti Afeez Oyétòrò)

Afeez Oyétòrò (tí wọ́n bí ní ogúnjọ́ oṣù Kẹjọ ọdún 1963), jẹ́ adérìnínú-pòṣónú, òṣèré sinimá àti ọ̀mọ̀wé ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Òun ni gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Sàká.[2][3][4]

Afeez Oyétòrò
Ọjọ́ìbí20 Oṣù Kẹjọ 1963 (1963-08-20) (ọmọ ọdún 61)
Ìsẹ́yìm, Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Nàìjíríà
Orúkọ mírànSàká
Ọmọ orílẹ̀-èdèNaijiria
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity of Ìbàdàn
Ọbáfẹmi Awólọ́wọ̀ University
Iṣẹ́
  • Òṣèré* Aláwàdà* ọ̀mọ̀wé
Notable workThe Wedding Party 2
Parent(s)Pa Oyétòrò (bàbá rẹ̀)[1]

Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀

àtúnṣe

Wọ́n bí Afeez ní Ìlú Ìsẹ́yìnÌpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. [5][6] Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè akọ́kọ́ àti èkejì nínú ìmọ̀ Theatre art láti ilé-ẹ̀kọ́ Ọbáfẹmi Awólọ́wọ̀ University àti University of Ìbàdàn. Ó sì ń kẹ́kọ̀ọ́ sì lọ́wọ́ láti gba oyè ọ̀mọ̀wé ní Fásitì Ìlú Ìbàdàn lọ́wọ́.[7]

Isẹ́ rẹ̀

àtúnṣe

Afeez di ìlú-mọ̀ọ́ká látàrí ipa rẹ̀ tí ó ma ń kó nínú eré gẹ́gẹ́ bí aláwadà ati adẹ́rín-pòṣónú ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà[8] Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olùkọ́ ní ẹ̀ka ẹ̀kọ́ ìmọ eré oníṣe nílé ẹ̀kọ́ olùkọ́ ti Adéníran Ògúnsànyà College of Education tí ó wà ní Ìpínlẹ̀ Èkó.[9] Ó jẹ́ ọkan lára àwọn olùpolówó fún MTN ní ọdún 2013 tí gbólóhùn rẹ̀ yí "I don port o." sì gba ìgboro kan. Ní ọdún 2016, ó kópa nínú eré The Wedding Party àti nínú eré aláwàdà ti Ojukokoro.[10]

Ìgbé ayé rẹ̀

àtúnṣe

Afeez gbé aya rẹ̀ Ọláídé Oyétòrò níyàwó, wọ́n bímọ ọkùrin méjì Abdullahi Oyétòrò àti Munim Oyétòrò àti ọmọ obìnrin kan ṣoṣo Rufiat Oyétòrò.[11][12]

Àwọn Fíìmú tí ó ti k'ópa ni

àtúnṣe

See also

àtúnṣe

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "MTN Ambassador, Saka looses father". nigeriapoliticsonline.com. Archived from the original on 16 February 2015. Retrieved 16 February 2015.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. "From bread and beans to BlackBerry studio". The Punch - Nigeria's Most Widely Read Newspaper. Archived from the original on 16 February 2015. Retrieved 16 February 2015.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. "In Girlz Hostel, Oyetoro rules as caretaker". The Punch - Nigeria's Most Widely Read Newspaper. Archived from the original on 16 February 2015. Retrieved 16 February 2015.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  4. Editor. "Comic actor, Saka honoured as he turns 50 - Nigerian Entertainment Today - Nigeria's Number 1 Entertainment Daily". Nigerian Entertainment Today - Nigeria's Number 1 Entertainment Daily. Archived from the original on 16 February 2015. Retrieved 16 February 2015.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. Latestnigeriannews. "Celebrity Birthday: Port Master, Afeez Oyetoro Turns 50". Latest Nigerian News. Retrieved 16 February 2015. 
  6. "Saka returns to his secondary school". The Punch - Nigeria's Most Widely Read Newspaper. Archived from the original on 16 February 2015. Retrieved 16 February 2015.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  7. "Saka I Don Port Unveiled, Articles - THISDAY LIVE". thisdaylive.com. Archived from the original on 16 February 2015. Retrieved 16 February 2015.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  8. "My Level Has Changed - P.M. NEWS Nigeria". pmnewsnigeria.com. Retrieved 16 February 2015. 
  9. "Midnight fire wreaks havoc at AOCOED". Vanguard News. Retrieved 16 February 2015. 
  10. "Ali Nuhu, Hafiz Ayetoro, others shine in new Nollywood film, Ojukokoro - Premium Times Nigeria" (in en-GB). Premium Times Nigeria. 2017-01-18. https://www.premiumtimesng.com/arts-entertainment/nollywood-nigeria/220881-ali-nuhu-hafiz-ayetoro-others-shine-new-nollywood-film-ojukokoro.html. 
  11. "‘Why I married late’ – Afeez Oyetoro" (in en-US). Encomium Magazine. http://encomium.ng/why-i-married-late-afeez-oyetoro/. 
  12. Bodunrin, Sola (2016-05-06). "Check out 15 popular Yoruba actors’ wives you don’t know (photos)" (in en-US). Naija.ng - Nigeria news.. https://www.naij.com/822570-check-15-popular-yoruba-actors-wives-dont-know-photos.html.