Agaricocrinus
Agaricocrinus jẹ́ ìdílé crinoid tí a kò rí mọ́, tí ó wà ní ẹbí Coelocrinidae.
Agaricocrinus | |
---|---|
Agaricocrinus splendens | |
Ìṣètò onísáyẹ́nsì | |
Ìjọba: | |
Ará: | |
Ẹgbẹ́: | |
Ìdílé: | |
Ìbátan: | Agaricocrinus Austin 1851
|
Àwọn tí wọ́n ń gbé ní òkè epifaunal tí wọ́n ń tòrò mọ́ nkan tí wọ́n maa jẹ yìí wà ní Ìgbà Eléèédú àti àkókó Osagean tí United States, lati 353.8 sí 345.0 Ma. [2]
Àwọn ẹ̀yà tí à ṣà
àtúnṣe- Agaricocrinus americanus Roemer
- Agaricocrinus splendens Miller and Gurley
Àpèjúwe
àtúnṣeBíi àwọn crinoid, ẹ̀yà Agaricocrinus maa ń ta mọ́ ojú ibi tóbà le.[3]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "The Paleobiology Database". Archived from the original on 2018-08-18. Retrieved 2016-06-27.
- ↑ Meyer, David L.; Ausich, William I. (1997). "Morphologic Variation within and among Populations of the Camerate Crinoid Agaricocrinus (Lower Mississippian, Kentucky and Tennessee): Breaking the Spell of the Mushroom". Journal of Paleontology 71 (5): 896–917. JSTOR 1306565.
- ↑ Dorit, R. L.; Walker, W. F.; Barnes, R. D. (1991). Zoology. Saunders College Publishing. pp. 790–792. ISBN 978-0-03-030504-7.