Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Gúúsù-Ìwọòrùn Ìbàdàn

Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́

Agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ Gúúsù-Ìwọ̀òrùn Ìbàdàn jẹ́ ọ̀kan lára àwọn agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ tó wà ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, ní Nàìjíríà. Olú-ìlú rẹ̀ wà ní Oluyole Estate ní Ìbàdàn. Àwọn agbègbè tó wà ní ìlú náà ni Ring-Road, Oke-Ado, Oke-Bola Gege, Born-Photo, àti Isale-Osi.

Ibadan South-West
Country Nigeria
StateOyo State
Government
 • Local Government Chairman and the Head of the Local Government CouncilKehinde Adeyemi Akanni (PDP)
Time zoneUTC+1 (WAT)

Ó ní ìwọ̀n ilẹ̀ tó tó 40 km2 àti iye ènìyàn tó tó 282,585 ni ìka orí tó wáyé ní ọdún 2006.

Kóòdù ìfìwéránṣẹ́ agbègbè náà ni 200.[1]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Post Offices – with map of LGA". NIPOST. Archived from the original on 2009-10-07. Retrieved 2009-10-20.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)