Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Efon
(Àtúnjúwe láti Agbegbe Ijoba Ibile Efon)
Efon jẹ́ ọ̀kan lára àwọn agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ tó wà ní Ìpínlẹ̀ Èkìtì, ní ìlú Nàìjíríà. Olú-ìlú rẹ̀ wà ní Efon-Alaaye.[1]
Efon | |
---|---|
LGA and town | |
Coordinates: 7°22′0″N 3°38′0″E / 7.36667°N 3.63333°ECoordinates: 7°22′0″N 3°38′0″E / 7.36667°N 3.63333°E | |
Country | Nigeria |
State | Ekiti State |
Government | |
• Local Government Chairman and the Head of the Local Government Council | Peter Daramola |
• Local Government Secretary | J.S Afolayan |
Time zone | UTC+1 (WAT) |
Wíwọ̀n ilẹ̀ yìí tó 232 km2, ó sì ní iye ènìyàn tó ń lọ bíi 86,941 nígbà tí wọ́n ka orí kọ̀ọ̀kan ní ọdún 2006. Nọ́ḿbà ìfìwéránṣẹ́ agbègbè náà ni 362.[2]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Efon – Ekiti State Website". Ekiti State Website – Official Website of the Government of Ekiti State. 2019-09-15. Retrieved 2023-01-13.
- ↑ "Post Offices- with map of LGA". NIPOST. Archived from the original on 2009-10-07. Retrieved 2009-10-20. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)