Alákàn
Taxonomy not available for Brachyura; please create it automated assistant
Alákàn tàbí Akàn tí wọ́n ń dà pè ní decapod ní èdè Gẹ̀ẹ́sì jẹ́ ẹranko tí ó lè gbé lórí ilẹ̀ àti inú omí. (Gíríkì: βραχύς = short,[2] οὐρά / οura = tail[3]) Ẹranko yí ma ń gbé nínú pàlà pálá ihò ilẹ̀ tàbí abẹ́ àwọn ewéko ní etí omi. Bákan náà ni kò sí ibi tí wọn kò sí ní orílẹ̀ àgbáyé pátá.
Crab | |
---|---|
Grey swimming crab Liocarcinus vernalis | |
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ e ] | |
Sections and subsections[1] | |
Ìrísí rẹ̀
àtúnṣeAlákàn jẹ́ ẹranko tí gbogbo egungun ara rẹ̀ wà ní ìta tí àwọn ẹran rẹ̀ sì sá pamọ́ sí inú ihò egungun ara rẹ̀. Ó sábà ma ń ní ẹsẹ̀ mẹ́fà; mẹ́ta lọ́tùn ún mẹ́ta lósì, bẹ́ẹ̀ ni ó ní kiní kan bí ìlédìí kọ̀kan lọ́tún àti lósì, tí ó sì tún ní ọwọ́ méjì níwájú tí ọwọ́ náà sì tún ní ẹ̀mú (pincer) tí ó fi ma ń dáàbò bo ara rẹ̀ lọ́wọ́ ewu.
Oríṣi Akàn tó wà
àtúnṣeOríṣríṣi akàn tí ó wà ni ó ní orúkọ tí wọ́n ń oè wọ́n ní agbègbè tí wọ́n bá wà ní orílẹ̀ àgbáyé. Lára orúkọ àti oríṣi akàn tí ó wà ni:
- Akàn gbògbó
- Akàn Òkun
- Akàn Ọ̀sà àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ
Àwọn Ìtọ́ka sí
àtúnṣe- ↑ Sammy De GraveÀsìṣe ìgbéọ̀rọ̀sílẹ̀: Àìdámọ̀ ọ̀rọ̀ "etal". (2009). "A classification of living and fossil genera of decapod crustaceans" (PDF). Raffles Bulletin of Zoology Suppl. 21: 1–109. Archived from the original on 2011-06-06. https://web.archive.org/web/20110606064728/http://rmbr.nus.edu.sg/rbz/biblio/s21/s21rbz1-109.pdf.
- ↑ Henry George Liddell; Robert Scott. "βραχύς". A Greek–English Lexicon. Perseus Digital Library. Retrieved 2010-05-24.
- ↑ Henry George Liddell; Robert Scott. "οὐρά". A Greek–English Lexicon. Perseus Digital Library. Retrieved 2010-05-24.