Aloma Mariam Mukhtar
Aloma Mariam Mukhtar tí a bí ní ogúnjọ́ oṣù kọkànlá, ọdún 1944 ní Ìpínlẹ̀ Kano jẹ́ adájọ́ àgbà fún ilé-ẹjọ́ àgbà Ilé-Ẹjọ́ gígajùlọ ilẹ̀ Nàìjíríà ní ọdún 2012,[1] gẹ́gẹ́ bí adelé fún adájọ́ Dahiru Musdapher tó fẹ̀yìntì. Òun ni adájọ́ àgbà obìnrin àkọ́kọ́ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà[2].
Aloma Mariam Mukhtar | |
---|---|
13k Olùdájọ́ Àgbà ilẹ̀ Nàìjíríà | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 16 July 2012 | |
Asíwájú | Dahiru Musdapher |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 20 Oṣù Kọkànlá 1944 Kano, Ipinle Kano, Naijiria |
Ààrẹ Goodluck Jonathan ṣe ìbúra ìwọlé fún Mukhtar ní ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù keje gẹ́gẹ́ bí Chief Justice of Nigeria, ó sì gba àmì-ẹ̀yẹ Nigerian National Honour ti adarí tó ga jù Order of the Niger (GCON).[3]
Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀
àtúnṣeWọ́n bí Mukhtar ní Ìpínlẹ̀ Adamawa[4] Ó bẹ̀rẹ̀ ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ni ilé-ẹ̀kọ́ Saint. George tí ó wà ní ìlú Zaria, ó sì tún lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ St. Bartholomew’s tí ó wà ní, Wusasa, Zaria, ó sì tún lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ Rossholme School for Girls, tí ó wà ní East Brent, Somerset, ní orílẹ̀-èdè England, bákan náà ni ó lọ sí Reading Technical College, Reading, Berkshire àti Gibson and Weldon College of Law, ní orílẹ̀-èdè England yìí kan náà. Lẹ́yìn ẹ̀kó rẹ̀ yí ni wọ́n pè é sí iṣẹ́ aṣòfin ní ilé-ìgbà-ẹ́jọ́ Gẹ̀ẹ́sì in absentia ní oṣù kọkànlá, ọdún 1966.[5]
Iṣẹ́ rẹ̀
àtúnṣeMukhtar bẹ̀rẹ̀ iṣẹ rẹ ní ọdún 1967, bíi olùdámọ̀ràn fún Ministry of Justice, Northern Nigeria a gbé ga:[6][7]
- Office of the Legal Draftsman, Interim Common Services Agency, Magistrate Grade I, North Eastern State Government, 1971
- Chief Registrar, Kano State Government Judiciary, 1973
- Judge of the High Court of Kano State, 1977—1987
- Justice of the Court of Appeal of Nigeria, Ibadan division, 1987—1993
- Justice of the Supreme Court of Nigeria, 2005—2012
- Justice of the Supreme Court of The Gambia 2011-2012
- Chief Justice of Nigeria, 2012—2014
Nínú iṣẹ rẹ , Mukhtar jẹ ẹni to se ipokinifirst obìnrin agbẹjọro kínní lawyer lati Northern Nigeria, obìnrin adájọ akọkọ High Court ni ile Kano State ìdájọ, obìnrin adájọ akọkọ Court of Appeal of Nigeria, obìnrin akọkọ justice ti Supreme Court of Nigeria (certain sources have erroneously given Roseline Ukeje this honor[8][9]) obìnrin akọkọ Chief Justice of Nigeria.[5]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Justice Aloma Mukhtar: A daunting task ahead". Archived from the original on 2014-07-25. Retrieved 2012-07-16.
- ↑ Justice Aloma Mukhtar: Will a woman make a difference?
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedTN
- ↑ Lawal, Dare. "What a woman! 10 things you did not know about Nigeria's immediate past chief justice, Aloma Mukhtar - The ScoopNG". The Scoop. Archived from the original on 1 July 2019. https://web.archive.org/web/20190701150638/https://thescoopng.com/2014/11/28/woman-10-things-know-nigerias-immediate-past-chief-justice-aloma-mukhtar/.
- ↑ 5.0 5.1 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedBD
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedPM
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedTN2
- ↑ Bauer, Gretchen; Dawuni, Josephine (2015-10-30). Gender and the Judiciary in Africa: From Obscurity to Parity?. Routledge. ISBN 9781317516491. https://books.google.com/books?id=ILDhCgAAQBAJ&pg=PA77.
- ↑ Aka, Jubril Olabode (February 2012). Nigerian Women of Distinction, Honour and Exemplary Presidential Qualities: Equal Opportunities for All Genders (White, Black Or Coloured People). Trafford Publishing. ISBN 9781466915541. https://books.google.com/books?id=A0I5gsKiDasC&pg=PA206.