Amélie Simone Mauresmo pípè ní Faransé: [ameli simɔn moʁɛsmo]; (ojoibi 5 July 1979) je agba tenis ara Fransi to ti feyinti, ati eni Ipo No. 1 Lagbaye tele. Mauresmo gba ife-eye won two Grand Slam awon enikan meji ni Australian Open ati Wimbledon.

Amélie Mauresmo
Amélie Mauresmo at the 2009 US Open 04.jpg
Orílẹ̀-èdèFránsì Fránsì
IbùgbéGeneva, Switzerland
Ọjọ́ìbí5 Oṣù Keje 1979 (1979-07-05) (ọmọ ọdún 40)
Saint-Germain-en-Laye, France
Ìga1.75 m (5 ft 9 in)
Ìgbà tódi oníwọ̀fà1994
Ìgbà tó fẹ̀yìntì3 December 2009
Ọwọ́ ìgbáyòRight-handed (one-handed backhand)
Ẹ̀bùn owóUS$14,992,112
Iye ìdíje544–226 (70.65%)
Iye ife-ẹ̀yẹ25 (2 ITF)
Ipò rẹ̀ gígajùlọNo. 1 (13 September 2004)
Open AustrálíàW (2006)
Open FránsìQF (2003, 2004)
WimbledonW (2006)
Open Amẹ́ríkàSF (2002, 2006)
Ìdíje WTAW (2005)
Ìdíje ÒlímpíkìSilver medal.svgFàdákà (2004)
Iye ìdíje92–62
Iye ife-ẹ̀yẹ3 (2 ITF)
Ipò rẹ̀ gígajùlọNo. 29 (26 June 2006)
Open AustrálíàQF (1999)
Open Fránsì2R (1997, 1998)
WimbledonF (2005)
Open Amẹ́ríkà3R (1999)
Last updated on: 31 August 2009.
Iye ẹ̀ṣọ́ Olympiki
Adíje fún Fránsì Fránsì
Tennis
Fàdákà 2004 Athens Ẹnìkan


ItokasiÀtúnṣe