Andre Kirk Agassi (play /ˈɑːndr ˈæɡəsi/; ojoibi ojo 29 osu kerin, 1970, ni Las Vegas, Nevada) je agba tennis to ti feyinti ara Amerika ati Eni ipo 1k Lagbaye tele, to je ikan ninu awon otayo to gbongan julo lati ibere awon odun 1990 de arin awon odun 2000.[1]

Andre Agassi
Andre Agassi Indian Wells 2006.jpg
Orúkọ Andre Kirk Agassi
Orílẹ̀-èdè USA USA
Ibùgbé Las Vegas, Nevada, United States
Ọjọ́ìbí Oṣù Kẹrin 29, 1970 (1970-04-29) (ọmọ ọdún 49)
Las Vegas, Nevada, United States
Ìga 1.80 m (5 ft 11 in)
Ìgbà tódi oníwọ̀fà 1986
Ìgbà tó fẹ̀yìntì September 3, 2006
Ọwọ́ ìgbáyò Right-handed (two-handed backhand)
Ẹ̀bùn owó

$31,152,975

Ilé àwọn Akọni 2011 (member page)
Iye ìdíje 870–274 (76.05% on the Grand Prix tour, ATP Tour, in Grand Slams and Davis Cup)
Iye ife-ẹ̀yẹ 60 (in Grand Prix and ATP Tour play and 68 in total)
Ipò rẹ̀ gígajùlọ No. 1 (April 10, 1995)
Open Austrálíà W (1995, 2000, 2001, 2003)
Open Fránsì W (1999)
Wimbledon W (1992)
Open Amẹ́ríkà W (1994, 1999)
Ìdíje ATP W (1990)
Ìdíje Òlímpíkì Gold medal.svg Gold medal (1996)
Iye ìdíje 40-42 (on the Grand Prix tour, ATP Tour, in Grand Slams and Davis Cup)
Iye ife-ẹ̀yẹ 1 (In Grand Prix and ATP Tour play)
Ipò rẹ̀ gígajùlọ No. 123 (August 17, 1992)
Open Fránsì QF (1992)
Open Amẹ́ríkà 1R (1987)
Davis Cup W (1990, 1992)
Iye ẹ̀ṣọ́ Olympiki
Men's tennis
Adíje fún USA USA
Wúrà 1996 Atlanta SinglesItokasiÀtúnṣe

  1. "Bio:Andre Agassi". Biography Channel. Retrieved January 27, 2011.