Annie Okonkwo

Oloselu Naijiria

Annie Okonkwo je Alagba ni Ile Alagba Asofin Naijiria lati 2007 doni.

Clement Annie Okonkwo
Senator for Anambra Central
In office
29 May 2007 – May 2011
AsíwájúEmmanuel Anosike
Arọ́pòChris Ngige
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí23 Oṣù Kàrún 1960 (1960-05-23) (ọmọ ọdún 63)
Ojoto, Anambra State, Nigeria

Clement Annie Okonkwo (ti a bí ni ojó ketalelogun oṣù kàrún ọdún 1960) ọ dibo ile asofin fun agbegbe aarin Anambra Anambra State, Nigeria, iṣẹ beere ni ojó kokandinlogbon osu karún ọdún 2007. Ọkàn lára ọmọ ẹgbẹ́ People's Democratic Party (PDP).[1]

Okonkwo ẹni tí a bí ni ojo ketalelogun oṣù kàrún ọdún 1960 ní Ojoto, l'ẹba Onitsha ni Anambra State.[2] O ka ìwé síwájú sí láti gbà diploma nínú ìsàkóso, Harvard University, USA (1997-1998), ìwé síwájú Diploma nínú oníṣòwò ofin ati ìwà, University of Lagos (1995-1997) pẹlu diploma síwájú sí nínú ìpolówó ọjà, University of Lagos (1994 - 1995).[1] Nínú ìṣòwò, o kò ilé iṣẹ nla ti ọ gbà egberun méje ènìyàn ní àwọn ilé iṣẹ Reliance Telecomm, Clemco Industries, Modern Communications (satellite TV Network), MacClemm Marketing Communications, Sunflower Nigeria and Pentagon Oil.[2]

Lẹyìn tí ọ gbà àga gẹgẹ bí olóṣèlú, a Yàn láti sójú ìgbìmò lori Upstream Petroleum Resources, ọrọ awọn ọlọpa, agbegbe (vice-chairman) ati ọgbin.[1] Nínú ayẹwo iṣẹ awọn olóṣèlú ni oṣù kàrún ọdún 2009, ThisDay se àpèjúwe okonkwo gẹgẹ bí ẹni tí ọ fi múlẹ láti jẹ kí ohun ọgbin àti oúnjẹ din owó fún ará ìlú àti awọn ara òke òkun ile Naijiria le ri ra .[3] Ni oṣù Kejì ọdún 2010 o di je Anambra State bí gomina.[4] sibẹsibẹ, o pa danu sí ọwọ gomina ti a Yàn , Peter Obi,[5]

Itokasi àtúnṣe

  1. 1.0 1.1 1.2 "Sen. Annie Okonkwo". National Assembly of Nigeria. Archived from the original on 2016-03-03. Retrieved 2010-06-15.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. 2.0 2.1 "About Annie". Annie Okonkwo. Archived from the original on 14 June 2009. Retrieved 2010-06-15.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. "An Improved Senate, But Some Uninspiring Senators...". ThisDay. 24 May 2009. Retrieved 2010-06-15. 
  4. Charles Onyekamuo (30 August 2009). "Okonkwo Vs Obi - A Paradoxical Challenge". ThisDay. Retrieved 2010-06-15. 
  5. "Obi Re-elected Anambra State Governor...(UPDATED)". ThisDay. 2 July 2010. Archived from the original on 12 February 2010. Retrieved 2010-02-07.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)