Annonaceae
Annonaceae wá láti ẹ̀yà igi eléso tó ní àwọn igi àti igi kúkurú bákan náà[3] tí wọ́n sì máa ń pè é ní custard apple family[4][3] tàbí soursop family. Ó ní genera 108 àti ẹ̀yà 2400 mìíràn,[5] òun sì ló pọ̀ jù nínú ìdílé Magnoliales. Oríṣiríṣi genera ló máa ń ṣẹ̀dá èso tó ṣe é jẹ. Èyí tó gbajúmọ̀ jù lọ ni Annona, Anonidium, Asimina, Rollinia, àti Uvaria. Ẹ̀ya rẹ̀ jẹ́ Annona.
Annonaceae | |
---|---|
Annona squamosa fruit | |
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ e ] | |
Type genus | |
Annona | |
Subfamilies | |
| |
Synonyms | |
Bí ó ti rí
àtúnṣeẸ̀yà rẹ̀ máa ń jẹ́ igi kékeré tàbí igi ńlá nígbà mìíràn, pẹ̀lú èpo-igi, ewé àti òdòdó.[6]
- Ẹ̀ka, ara àti ewé
- Èpò igi rẹ̀ ki, ó sì ní òórùn dídùn. Pith septate rẹ̀ pín sí oríṣiríṣi ọ̀nà[7] tí wọ́n sì ní ilà ní àárín.[6] Ẹ̀ka rẹ pín sí méjì, ó sì lọ pọ̀ mọ́ra wọn.[8] Ewé rẹ̀ ní ìpele méjì, ó sì nílà lára.[6]
Àwòrán onígi
àtúnṣe
|
Annonaceae |
| ||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Magnoliales". www.mobot.org. Retrieved 2023-06-18.
- ↑ Germplasm Resources Information Network (GRIN) (2007-05-12). "Family: Annonaceae Juss., nom. cons.". Taxonomy for Plants. USDA, ARS, National Genetic Resources Program, National Germplasm Resources Laboratory, Beltsville, Maryland. Retrieved 2008-04-18.
- ↑ 3.0 3.1 Flora of North America. 2. Annonaceae Jussieu. 3. http://www.efloras.org/florataxon.aspx?flora_id=1&taxon_id=10047. Retrieved 2008-04-20.
- ↑ Àdàkọ:ITIS
- ↑ Chatrou, L.W.; M.D. Pirie; R.H.J. Erkens; T.L.P. Couvreur; K. M. Neubig; J.R. Abbott; J.B. Mols; P.J.M. Maas et al. (2012). "A new subfamilial and tribal classification of the pantropical flowering plant family Annonaceae informed by molecular phylogenetics". Botanical Journal of the Linnean Society 169: S. 4–50. doi:10.1111/j.1095-8339.2012.01235.x.
- ↑ 6.0 6.1 6.2 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedFNA2
- ↑ Chatrou, Dr. L.W. (2005-07-29). "Molecular Systematics of Annonaceae". Annonaceae Research Projects (Nationaal Herbarium Nederland). http://www.nationaalherbarium.nl/taskforcemolecular/annonaceae.htm#Molecular%20Systematics%20of%20Annonaceae. Retrieved 2008-04-20.
- ↑ Johnson, D.M. (July–September 2003). "Phylogenetic significance of spiral and distichous architecture in the Annonaceae". Systematic Botany 28 (3): 503–511. doi:10.1043/02-13.1. https://bioone.org/journals/Systematic-Botany/volume-28/issue-3/02-13.1/Phylogenetic-Significance-of-Spiral-and-Distichous-Architecture-in-the-Annonaceae/10.1043/02-13.1.short.