Apaadi
Apaadi jẹ́ fíìmù Yorùbá ti ilẹ̀ ọdún 2009. Ó jẹ́ fíìmù adá-lórí-ìtàn-gidi, èyí tí Funke Akindele máa kọ́kọ́ ṣe, òun náà sì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn akópa eré náà. Africa Movie Academy Awards yan fíìmù náà ní ọdún 2009, fún fíìmù tó dára jù lọ ní èdè Afrika àti ìṣeyege nínú asọ eré. Wọ́n sì yan Femi Adebayo fún òṣèrékùnrin tó dára jù, fún ìkópa rẹ̀ nínú eré náà.[1]
Apaadi | |
---|---|
Adarí | Abiodun Olanrewaju |
Olùgbékalẹ̀ | Funke Akindele |
Àwọn òṣèré | Funke Akindele Femi Adebayo Yinka Quadri Taiwo Hassan Adebayo Salami Ronke Odusanya Peju Ogunmola Opeyemi Aiyeola Sola Kosoko Moji Olaiya Lola Margret Peter Fatomilola |
Ilé-iṣẹ́ fíìmù | Scene One Productions |
Olùpín | Olasco Films Nig. Ltd. |
Orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Èdè | Yoruba |
Àwọn àmì-ẹ̀ye àti yíyàn fún àmì-ẹ̀yẹ
àtúnṣeỌdún | Àmì-ẹ̀yẹ | Ìsọ̀rí | Olùgbà | Èsì | Ìtọ́ka |
---|---|---|---|---|---|
2009 | Africa Movie Academy Awards | Best Film in African Language | Apaadi | Wọ́n pèé | [2] |
Achievement in Costume | Apaadi | Wọ́n pèé | |||
Best Supporting Actor | Femi Adebayo | Wọ́n pèé |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "AMAA 2009 - Artistes At War". The Daily Independent (Lagos). 3 April 2009. http://allafrica.com/stories/200904030357.html?viewall=1. Retrieved 11 October 2010.
- ↑ "Apaadi is a Nollywood Yoruba language film released in 2009.". Pulse ng. Archived from the original on 2023-05-11. Retrieved 2024-03-09.