Arthur Robert Ashe, Jr.(July 10, 1943 – February 6, 1993) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfasẹ́ gbá tenis, tí wọ́n bí, tó dàgb̀a, sí Richmond, Virginia. Nípa iṣẹ́ bọ́ọ̀lù rẹ̀, ó jáwé olúborí tí ́ó sì gba ife-ẹ̀yẹ Grand Slam mẹ́ta, èyí tí ó sò di ìkan nínú àwọn tó dára jùlọ nínú tenis ní Amẹ́ríkà. Ashe, tí ó jẹ́ ọmọ Afrika Ameríkà, tún jẹ́ riranti fun akitiyan re fun ilosiwaju awujo.

Arthur Ashe
C9186-21Reagan-Ashe.jpg
Arthur Ashe greets President Reagan in 1982
Orílẹ̀-èdè USA USA
Ibùgbé Petersburg, Virginia
Ìga 6 ft 1 in (1.85 m)
Ìgbà tódi oníwọ̀fà 1969
Ìgbà tó fẹ̀yìntì 1980
Ọwọ́ ìgbáyò Right-handed; one-handed backhand
Ẹ̀bùn owó US$2,584,909
Ilé àwọn Akọni 1985 (member page)
Iye ìdíje 818-260
Iye ife-ẹ̀yẹ 33
Ipò rẹ̀ gígajùlọ No. 1 (1969)
Open Austrálíà W (1970)
Open Fránsì QF (1970, 1971)
Wimbledon W (1975)
Open Amẹ́ríkà W (1968)
Iye ìdíje 315–173
Iye ife-ẹ̀yẹ 18
Last updated on: July 24, 2007.

ItokasiÀtúnṣe