Afghanístàn tabi Orile-ede Onimale Olominira ile Afghanistan je orile-ede ni Ásíà.

Islamic Republic of Afghanistan
جمهوری اسلامی افغانستان
(Àdàkọ:Lang-fa)
د افغانستان اسلامي جمهوریت
(Pashtó: Da Afġānistān Islāmī Jomhoriyat)
Orin-ìyìn orílẹ̀-èdèMilli Surood
Olúìlú
(àti ìlú títóbijùlọ)
Kabul
34°31′N 69°08′E / 34.517°N 69.133°E / 34.517; 69.133
Èdè àlòṣiṣẹ́ Dari (Persian), Pashto[1]
Orúkọ aráàlú Ará Afghanistan
Ìjọba Islamic Republic
 -  President Hamid Karzai
 -  Vice President Mohammad Qasim Fahim
 -  Vice President Karim Khalili
 -  Chief Justice Abdul Salam Azimi
Establishment
 -  First Afghan state[2] October 1747 
 -  Independence from the United Kingdom August 19, 1919 
Ààlà
 -  Àpapọ̀ iye ààlà 647,500 km2 (41st)
251,772 sq mi 
 -  Omi (%) negligible
Alábùgbé
 -  Ìdíye 2009 28,150,000[3] (37th)
 -  1979 census 13,051,358 
 -  Ìṣúpọ̀ olùgbé 43.5/km2 (150th)
111.8/sq mi
GIO (PPP) ìdíye 2008
 -  Iye lápapọ̀ $21.388 billion[4] (96th)
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $760[4] (172nd)
GIO (onípípè) Ìdíye 2008
 -  Àpapọ̀ iye $11.709 billion[4] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $416[4] 
HDI (2007) 0.345 (low) (174)
Owóníná Afghani (AFN)
Àkókò ilẹ̀àmùrè D† (UTC+4:30)
Ìwakọ̀ ní ọwọ́ right
Àmìọ̀rọ̀ Internet .af
Àmìọ̀rọ̀o tẹlifóònù 93

Nínú ètò ìkànìyàn 1995, àwọn ènìyàn tí wọ́n sọ pé ó wà ní ìlú yìí lé díẹ̀ ní mílíònù mọ́kànlélógún (21,017.000). Èdè tí wọ́n ń sọ ní ìlú yìí tó àádọ́ta ṣùgbọ́n ìlàjì nínú àwọn tí ó wà ní ìlú náà ni ó ń sọ páṣítọ̀ (Pashto) tí òun àti Dárì jọ jẹ èdè ìjọba (official language). Dárì (Dari) yìí nì orúkọ tí wọ́n ń pe Persian (Pásíà) ní Afuganísítàànù. Dárí yìí ṣe pàtàkì gan-an ni gẹ́gẹ́ bí èdè tí ìjọba ń lò (lingua franca). Fún ti òwò tí ó jẹ mọ gbogbo àgbáyé, èdè Gẹ̀ẹ́sì ti ń gbilẹ̀ sí i. Àwọn èdè mìíràn tí wọ́n ń sọ ní ìlú yìí ni Tadzhik, Uzbek, Turkmen, baluchi, Brachic àti pashayi


ItokasiÀtúnṣe

  1. "Afghanistan". The World Factbook. Central Intelligence Agency. 2007-12-13. 
  2. "Afghanistan", CIA - The World Factbook 2007.
  3. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named unpop
  4. 4.0 4.1 4.2 4.3 "Afghanistan". International Monetary Fund. Retrieved 2009-10-01.