Augustina Ebhomien Sunday

Augustina Ebhomien Sunday (tí a bí ní ọjọ́ kẹtàlélógún, oṣù kẹjọ, ọdún 1996) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Naijiria tó ń gbá bọ́ọ̀lù badminton.[1][2] Ó kọ́ èkọ́ gboyè nínú èdè Gẹ̀ẹ́sì ní Benson Idahosa University, ní ọdún 2015, ó parí ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní Summer Universiade, ní ìlú Gwangju, ní orílẹ̀-èdè South Korea.[3]

Àwọn àṣeyọrí rẹ̀

àtúnṣe

Ìdíje ti ilẹ̀ Africa

àtúnṣe

Àdàpọ̀ àwọn obìnrin

Year Venue Partner Opponent Score Result
2019 Alfred Diete-Spiff Centre,

Port Harcourt, Nigeria

  Peace Orji   Amin Yop Christopher

  Chineye Ibere

16–21, 14–21   Bronze

Ìdíje ti gbogboogbò ti BWF

àtúnṣe

Àdàpọ̀ àwọn obìnrin

Year Tournament Partner Opponent Score Result
2014 Uganda International   Dorcas Ajoke Adesokan   Tosin Damilola Atolagbe

  Fatima Azeez

21–14, 9–21, 12–21 Runner-up
2013 Nigeria International   Deborah Ukeh   Tosin Damilola Atolagbe

  Fatima Azeez

21–18, 21–13 Winner

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe