Uchechukwu Deborah Ukeh
Uchechukwu Deborah ukeh (tí a bí ní ọjọ́ kejìlá, oṣù kọkànlá, ọdún 1996) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Naijiria tó ń gbá bọ́ọ̀lù badminton.[1] Níọdún 2014, ó kópa nínú ìdíje ti Africa Youth Games, ó sì gbé ipò àkọ́kọ́ ní èẹ̀meejì.[2] Ní ọdún 2016, òun ló gbégbá orókè ní ìdíje gbogboogbò tí ó wáyé ní Ivory Coast, ó sì tún gbéipò akọ́kọ́ nígbà tí ó fọwọsowọpọl pẹ̀lú Gideon Babalola.[3] Ní ọdún 2017, òun àti Babalola dé ipò akọ́kọ́ nínú ìdíje gbogboogbò ti Ivory Coast, àmọ́, ó gbé ipò kejì.[4] Ní ìdíje gbogboogbò tó wáyé ní Benin, Ukeh, tún gbé ipò kìíní.[5] Ní ìdíje tó wáyé ni Naijiria, ti Katsina Golden Star Badminton Championships, Ukeh náà ló ṣe aṣojú Ipinle Edo, òun náà ló gbégbá orókè.[6]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣeÌdíje ilẹ̀ Africa
àtúnṣeÌdàpọ̀ àwọn obìnrin
Year | Venue | Partner | Opponent | Score | Result |
---|---|---|---|---|---|
2019 | Ain Chock Indoor Sports Center,
Casablanca, Morocco |
Dorcas Ajoke Adesokan | Doha Hany | 9–21, 16–21 | Silver |
Ìdíje ilẹ̀ Africa
àtúnṣeÌdàpọ̀ àwọn obìnrin
Year | Venue | Partner | Opponent | Score | Result |
---|---|---|---|---|---|
2019 | Alfred Diete-Spiff Centre,
Port Harcourt, Nigeria |
Dorcas Ajoke Adesokan | Amin Yop Christopher | 21–14, 20–22, 21–17 | Gold |
2020 | Cairo Stadium Hall 2, | Dorcas Ajoke Adesokan | Doha Hany | 14–21, 17–21 | Silver |
Ìdíje fún àwọn ọ̀dọ́ Africa
àtúnṣeÌdàpọ̀ àwọn obìnrin
Year | Venue | Partner | Opponent | Score | Result |
---|---|---|---|---|---|
2014 | Otse Police College,
Gaborone, Botswana |
Usman Isiaq | Bongani von Bodenstein | 14–21, 21–19, 14–21 | Bronze |
Ìdíje gbogboogbò ti BWF
àtúnṣeÀwọn obìnrin nìkan
Year | Tournament | Opponent | Score | Result |
---|---|---|---|---|
2016 | Ivory Coast International | Lekha Shehani | 11–21, 14–21 | Runner-up |
2017 | Benin International | Dorcas Ajoke Adesokan | 7–21, 18–21 | Runner-up |
Ìdàpọ̀ àwọn obìnrin
Year | Tournament | Partner | Opponent | Score | Result |
---|---|---|---|---|---|
2013 | Nigeria International | Augustina Ebhomien Sunday | Tosin Damilola Atolagbe | 21–18, 21–13 | Winner |
2017 | Benin International | Peace Orji | Dorcas Ajoke Adesokan | 18–21, 21–16, 12–21 | Runner-up |
2019 | Ghana International | Dorcas Ajoke Adesokan | K. Maneesha | 11–21, 11–21 | Runner-up |
Ìdàpọ̀ àwọn obìnrin
Year | Tournament | Partner | Opponent | Score | Result |
---|---|---|---|---|---|
2016 | Ivory Coast International | Gideon Babalola | Tobiloba Oyewole | 21–7, 21–10 | Winner |
2017 | Ivory Coast International | Gideon Babalola | Enejoh Abah | Walkover | Runner-up |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Players: Uchechukwu Deborah Ukeh". Badminton World Federation. Retrieved 2 December 2016.
- ↑ "AYG: Team Nigeria bags 12 gold". Vanguard. Retrieved 13 November 2017.
- ↑ "Internationaux de Côte d’Ivoire – Résultats". Association Francophone de Badminton (in Èdè Faransé). Archived from the original on 14 November 2017. Retrieved 13 November 2017.
- ↑ "Internationaux Séniors de Badminton : Le Nigeria rafle 11 médailles !" (in Èdè Faransé). Regionale.info. Retrieved 13 November 2017.
- ↑ "Nigeria's Badminton Team Wins Benin Republic International". Sports Village Square. Retrieved 13 November 2017.
- ↑ "Krobakpor, Adesokan rule Katsina Badminton Championships". GongNews. Archived from the original on 14 November 2017. Retrieved 13 November 2017.