Open Austrálíà
Open Australia je ikan ninu awon idije Grand Slam merin to uwaye ninu ere-idaraya alagbase Tenis. O unwaye lodoodun ni Australia labe ase Tennis Australia, teletele tounje Egbe Ajose Tenis Australia (Lawn Tennis Association of Australia, LTAA) beesini idije akoko re waye lori papa isere kriket ni Melbourne ni 1905. Loni won unpe ibe ni Albert Reserve Tennis Centre.[2]
Open Austrálíà Australian Open | ||
---|---|---|
Official website | ||
Ibùdó | Melbourne Australia | |
Pápá | Melbourne Park | |
Orí pápá | Plexicushion Prestige | |
Men's draw | 128S / 128Q / 64D | |
Women's draw | 128S / 96Q / 64D | |
Ẹ̀bùn owó | A$23,140,000 (2009)[1] | |
Grand Slam | ||
Itan
àtúnṣeOpen Australia koko bere bi Idije-eye Australasia (Australasian Championships) ko to wa di Idije-eye Australia (Australian Championships), ni 1927 to si di Open Australia (Australian Open) ni 1969.[3]. Open Australia di sisi sile, eyun open, fun awon osise agba tenis ni odun 1969, odun kan leyin ti awon idije Grand Slam meta yioku ti di open fun awon osise agba tenis.[4]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ "Pay increase for AO winners". Australian Open. 11 January 2009. Retrieved 2009-01-17.
- ↑ "Australian Tennis Open History". Jazzsports. Archived from the original on 2008-01-30. Retrieved 22-01-2008. Check date values in:
|access-date=
(help) - ↑ Tristan Foenander. "History of the Australian Open – the Grand Slam of Asia/Pacific". Australian Open. Retrieved 22-01-2008. Check date values in:
|access-date=
(help) - ↑ "Australian History and Records". TennisTours.com. Archived from the original on 2008-12-21. Retrieved 17-01-2009. Check date values in:
|access-date=
(help)