Árgọ̀nù je elimenti kemika kan to ni ami-idamo Ar ati nomba atomu 18. O wa ninu egbe 18 (awon efuufu abiire) lori tabili idasiko awon elimenti. Argonu ni efuufu keta to wopo julo ninu afefeayika Aye, ni 0.93% (9,300 ppm), eyi so di eyi to repete ni ona bi 23.8 bi ti efuufu inu afefeayika tto wopo julo to tele, eyun dioksidi karbonu (390 ppm), ati to po repete ni ona to to 500 bi ti efuufu abiire keji to wopo, eyun neonu (18 ppm). Bi gbogbo argonu yi lo je argonu-40 radiogeniki to wa lati ituka potassium-40 ninu igbele Aye. Ni agbalaaye, argonu-36 ni isotopu argonu to wopo julo, nitoripe o je isotopu argonu to je dida pelu stellar ikojonukleu irawo ninu awon supanofa (awon irawo akomonamona).
Árgọ̀nù, 18Ar |
Árgọ̀nù |
---|
Pípè | /ˈɑːrɡɒn/ (AR-gon) |
---|
Ìhànsójú | colorless gas exhibiting a lilac/violet glow when placed in a high voltage electric field |
---|
Ìwúwo átọ̀mù Ar, std(Ar) | [39.792, 39.963] conventional: 39.95[1] |
---|
Árgọ̀nù ní orí tábìlì àyè |
---|
|
Nọ́mbà átọ̀mù (Z) | 18 |
---|
Ẹgbẹ́ | group 18 (noble gases) |
---|
Àyè | àyè 3 |
---|
Àdìpọ̀ | Àdìpọ̀-p |
---|
Ẹ̀ka ẹ́límẹ́ntì | Ẹ̀fúùfù abíire |
---|
Ìtò ẹ̀lẹ́ktrọ́nù | [Ne] 3s2 3p6 |
---|
Iye ẹ̀lẹ́ktrọ́nù lórí ìpele kọ̀ọ̀kan | 2, 8, 8 |
---|
Àwọn ohun ìní ara |
---|
Ìfarahàn at STP | gas |
---|
Ìgbà ìyọ́ | 83.80 K (−189.35 °C, −308.83 °F) |
---|
Ígbà ìhó | 87.30 K (−185.85 °C, −302.53 °F) |
---|
Kíki (at STP) | 1.784 g/L |
---|
when liquid (at b.p.) | 1.40 g/cm3 |
---|
Triple point | 83.8058 K, 69 kPa |
---|
Critical point | 150.87 K, 4.898 MPa |
---|
Heat of fusion | 1.18 kJ/mol |
---|
Heat of | 6.43 kJ/mol |
---|
Molar heat capacity | 5R/2 = 20.786 J/(mol·K) |
---|
pressure
P (Pa)
|
1
|
10
|
100
|
1 k
|
10 k
|
100 k
|
at T (K)
|
|
47
|
53
|
61
|
71
|
87
|
|
Atomic properties |
---|
Oxidation states | 0 |
---|
Electronegativity | Pauling scale: no data |
---|
energies | |
---|
Covalent radius | 106±10 pm |
---|
Van der Waals radius | 188 pm |
---|
Spectral lines of árgọ̀nù |
Other properties |
---|
Natural occurrence | primordial |
---|
Crystal structure | (fcc) |
---|
Speed of sound | (gas, 27 °C) 323 m/s |
---|
Thermal conductivity | 17.72x10-3 W/(m·K) |
---|
Magnetic ordering | diamagnetic[2] |
---|
CAS Number | 7440–37–1 |
---|
History |
---|
Discovery | Lord Rayleigh and William Ramsay (1894) |
---|
First isolation | Lord Rayleigh and William Ramsay (1894) |
---|
Main isotopes of árgọ̀nù |
---|
|
Àdàkọ:Category-inline | references |