Bẹ̀rmúdà
Bermuda (pípè /bɜrˈmjuːdə/; lonibise bi, àwọn Bẹ̀rmúdà tabi Àwọn Erékùṣù Somers) je ile-agbegbe okere Britani ni Ariwa Okun Atlantiki. O budo si ilaorun etiokun awon Ipinle Aparapo, isupoile to sunmo julo ni Cape Hatteras, North Carolina, bi 1,030 kilometres (640 mi) si iwoorun-ariwaiwoorun. O wa bi 1,373 kilometres (853 mi) guusu Halifax, Nova Scotia, Kanada, ati 1,770 kilometres (1,100 mi) ariwailaorun Miami, Florida. Oluilu re ni Hamilton sugbon ibile titobijulo ni ilu Saint George's.
Bẹ̀rmúdà | |
---|---|
Olùìlú | Hamilton |
Ìlú Ìbílẹ̀ | St. George's |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Gẹ̀ẹ́sì1 |
Èdè míràn | Portuguese1 |
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn | 54.8% African-Caribbean 34.1% white 6.4% multiracial 4.3% other 0.4% unspecified[1] |
Orúkọ aráàlú | Bermudian or Bermudan |
Ìjọba | Àwọn ilẹ̀ òkèrè Brítánì |
• Adobaje | Queen Elizabeth II |
• Gomina | Sir Richard Gozney |
• Asiwaju | Paula Cox |
Ìtóbi | |
• Total | 53.2 km2 (20.5 sq mi) (224th) |
• Omi (%) | 26% |
Alábùgbé | |
• 2009 estimate | 67,837[1] (199th) |
• 2000 census | 62,059 |
• Ìdìmọ́ra | 1,275/km2 (3,302.2/sq mi) (7th) |
GDP (PPP) | 2007[2] estimate |
• Total | $5.85 billion[2] (149th) |
• Per capita | $91,477[2] (1st) |
HDI (2003) | n/a Error: Invalid HDI value · n/a |
Owóníná | Bermudian dollar2 (BMD) |
Ibi àkókò | UTC-4 (Atlantic) |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | osi |
Àmì tẹlifóònù | +1-441 |
ISO 3166 code | BM |
Internet TLD | .bm |
|
Bermuda ni ile-agbegbe okere Britani toseku topejulo to si ni olugbe julo, o je bibudo si latowo Ilegeesi ni ogorun odun ki ofin Isoka 1707 to da Ileoba Britani Olokiki aparapo sile. Oluilu Bermuda akoko, St George's, je bibudo sori ni 1612 o si je ilu Ilegeesi ni Amerika topejulo ti awon eniyan ungbe nibe.[3]
Okowo Bermuda dara daada, pelu inawo bi eka okowo re totobijulo, leyin re ni isebewo,[3][4] awon wonyi fun ni GIO tenikookan to gajulo lagbaye ni 2005. O ni ojuojoabeonileoloru .[5]
Itokasi
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 Central Intelligence Agency (2009). "Bermuda". The World Factbook. Archived from the original on 4 June 2020. Retrieved 23 January 2010.
- ↑ 2.0 2.1 2.2 Bermuda leads in GDP per capita, The Royal Gazette, 07/12/08
- ↑ 3.0 3.1 "Bermuda - History and Heritage". Smithsonian.com. 6 November 2007. Archived from the original on 24 May 2012. Retrieved 3 December 2008.
- ↑ “Bermuda's Tourism Industry” Tayfun King, Fast Track, BBC World News (3 Nov. 2009)
- ↑ Forbes, Keith. "Bermuda Climate and Weather". The Royal Gazette. Retrieved 28 Oct. 2008. Check date values in:
|access-date=
(help)